YOR Isaiah Sura 58

Isaiah 58

YOR · Linganisha · Sauti

1Kígbe rẹ̀ sókè, má ṣe fàsẹ́yìn. 2Nítorí ọjọ́ dé ọjọ́ ni wọ́n ń wá mi kiri; 3Wọ́n wí pé, ‘Èéṣe tí àwa fi ń gbààwẹ̀, 4Àwẹ̀ yín sì parí nínú ìjà àti asọ̀, 5Ǹjẹ́ èyí ha ni irú àwẹ̀ tí mo yàn bí, Olúwa? 6“Ǹjẹ́ irú àwẹ̀ tí mo ti yàn kọ́ ni èyí: 7Kì í ha á ṣe láti pín oúnjẹ yín fún àwọn tí ebi ń pa 8Nígbà náà ni ìmọ́lẹ̀ rẹ yóò tàn jáde bí òwúrọ̀ Olúwa yóò sì jẹ́ ààbò lẹ́yìn rẹ. 9Nígbà yìí ni ẹ̀yin yóò pè, tí Olúwa yóò sì dáhùn; 10àti bí ẹ̀yin bá ná ara yín bí owó nítorí àwọn tí ebi ń pa 11Olúwa yóò máa tọ́ ọ yín nígbà gbogbo; 12Àwọn ènìyàn rẹ yóò tún ahoro àtijọ́ kọ́ 13“Bí ìwọ bá pa ẹsẹ̀ rẹ mọ́ kúrò nínú bíba ọjọ́ ìsinmi jẹ́, Olúwa ní ohun ọ̀wọ̀ 14nígbà náà ni ìwọ yóò ní ayọ̀ nínú Olúwa rẹ, Olúwa ni ó ti sọ̀rọ̀.

Kikomo cha Kila Siku Kimefikia

Boresha mpango wako ili kuendelea na matumizi ya vipengele vya AI na mipango ya juu ya kila siku.

Linganisha mipango yote →