Sakarja 9
1Ọ̀rọ̀-ìmọ̀. Olúwa kọjú ìjà sí Hadiraki, Olúwa ń bẹ lára ènìyàn, 2Àti Hamati pẹ̀lú yóò ṣe ààlà rẹ̀ 3Tire sì mọ odi líle fún ara rẹ̀, 4Ṣùgbọ́n, Olúwa yóò kó gbogbo ohun ìní rẹ̀ lọ, 5Aṣkeloni yóò rí í, yóò sì bẹ̀rù; 6Ọmọ àlè yóò sì gbé inú Aṣdodu, 7Èmi yóò sì mu ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ kúrò ni ẹnu rẹ̀, 8Èmi yóò sì dó yí ilẹ̀ mi ká 9Kún fún ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Sioni, 10Èmi ó sì gbé kẹ̀kẹ́ kúrò ni Efraimu, 11Ní tìrẹ, nítorí ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú mi pẹ̀lú rẹ, 12Ẹ padà sínú odi agbára yín, ẹ̀yin òǹdè ti o ni ìrètí: 13Èmi ó fa Juda le bí mo ṣe fa ọrun mi le, Olúwa yóò farahàn 14Olúwa yóò sì fi ara hàn ní orí wọn; Olúwa Olódùmarè yóò sì fọn ìpè, 15Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò dáàbò bò wọ́n; 16Olúwa Ọlọ́run wọn yóò sì gbà wọ́n là ni ọjọ́ náà 17Nítorí oore rẹ̀ tí tóbi tó, ẹwà rẹ̀ sì tí pọ̀!