YOR Obadja Kapitel 1

Obadja 1

YOR · Jämför · Ljud

1Ìran ti Obadiah. Olúwa Olódùmarè wí nípa Edomu. Olúwa wá, 2“Kíyèsi i, Èmi yóò sọ ọ́ di kékeré láàrín àwọn kèfèrí; 3Ìgbéraga àyà rẹ ti tàn ọ́ jẹ, 4Bí ìwọ tilẹ̀ gbé ara rẹ ga bí ẹyẹ idì, Olúwa wí. 5“Bí àwọn olè tọ̀ ọ́ wá, 6Báwo ni a ṣe ṣe àwárí nǹkan Esau, 7Gbogbo àwọn ẹni ìmùlẹ̀ rẹ 8Olúwa wí pé, “Ní ọjọ́ náà, 9A ó ṣe ẹ̀rù ba àwọn jagunjagun rẹ, ìwọ Temani, 10Nítorí ìwà ipá sí Jakọbu arákùnrin rẹ, 11Ní ọjọ́ tí ìwọ dúró ní apá kan, 12Ìwọ kì bá tí fi ojú kéré arákùnrin rẹ, 13Ìwọ kì bá tí wọ inú ibodè àwọn ènìyàn mi lọ, 14Ìwọ kì bá tí dúró ní ìkóríta ọ̀nà 15“Nítorí ọjọ́ Olúwa súnmọ́ etílé 16Gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀ ṣe mu lórí òkè mímọ́ mi, 17Ṣùgbọ́n ìgbàlà yóò wà lórí òkè Sioni, 18Ilé Jakọbu yóò sì jẹ́ iná Olúwa ti sọ̀rọ̀. 19Àwọn ará gúúsù yóò ni òkè Esau, 20Àwọn ìgbèkùn Israẹli tí ó wà ní Kenaani 21Àwọn tó ń gba ni là yóò sì gòkè Sioni wá Olúwa.

Ob · 1

Daglig gräns nådd

Uppgradera din plan för att fortsätta använda AI-funktioner med högre dagliga gränser.

Jämför alla planer →