Habackuk 1
1Àsọtẹ́lẹ̀ tí wòlíì Habakuku rí. 2Olúwa, èmi yóò ti ké pẹ́ tó fún ìrànlọ́wọ́, 3Èéṣe tí ìwọ fi mú mi rí àìṣedéédéé? 4Nítorí náà, òfin di ohun àìkàsí, Olúwa 5“Ẹ wo inú àwọn kèfèrí, ki ẹ sí wòye, 6Nítorí pé, èmi yóò gbé àwọn ara Babeli dìde, 7Wọn jẹ́ ènìyàn ti a bẹ̀rù, tí a sì páyà, 8Ẹṣin wọn yára ju ẹkùn lọ, 9gbogbo wọn sì wà fún ìwà ipá 10Wọn ó si máa fi àwọn ọba ṣẹ̀sín 11Nígbà náà ni inú rẹ̀ yóò yípadà, 12Olúwa, ǹjẹ́ láti ayérayé kọ ni ìwọ tí wà? Olúwa Ọlọ́run mi. Ẹni mímọ́ mi, àwa kì yóò kú Olúwa, ìwọ tí yàn wọn fún ìdájọ́; 13Ojú rẹ mọ́ tónítóní láti wo ibi; 14Ìwọ sì tí sọ ènìyàn di bí ẹja inú Òkun, 15Àwọn ènìyàn búburú fi àwọ̀n wọn gbé wọn sókè 16Nítorí náà, ó rú ẹbọ sí àwọ̀n rẹ̀, 17Ǹjẹ́ wọn yóò ha máa pa àwọ̀n wọn mọ́ ní òfìfo bí,