YOR Predikaren Kapitel 12

Predikaren 12

YOR · Jämför · Ljud

1Rántí Ẹlẹ́dàá rẹ 2kí oòrùn àti ìmọ́lẹ̀ 3nígbà tí olùṣọ́ ilé yóò wárìrì 4nígbà tí ìlẹ̀kùn sí ìgboro yóò tì 5Nígbà tí ènìyàn yóò bẹ̀rù ibi gíga 6Rántí rẹ̀ kí okùn fàdákà tó já, 7Tí erùpẹ̀ yóò sì padà sí ilẹ̀ ibi tí ó ti wà, 8“Asán! Asán!” ni Oniwaasu wí. 9Kì í ṣe wí pé Oniwaasu jẹ́ ọlọ́gbọ́n nìkan, ṣùgbọ́n ó tún kọ́ àwọn ènìyàn ní ìmọ̀. Ó rò ó dáradára ó sì ṣe àwárí, ó sì gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe kalẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ. 10Oniwaasu wádìí láti rí àwọn ọ̀rọ̀ tí ó tọ̀nà, ohun tí ó kọ sì dúró ṣinṣin ó sì jẹ́ òtítọ́. 11Ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n dàbí ẹ̀gún, àkójọpọ̀ ọ̀rọ̀ wọn sì dàbí ìṣó tí a kàn pọ̀ dáradára, tí olùṣọ́-àgùntàn kan fi fún ni. 12Àti síwájú láti inú èyí, ọmọ mi, gba ìmọ̀ràn. 13Nísinsin yìí, 14Nítorí Ọlọ́run yóò ṣe ìdájọ́ olúkúlùkù iṣẹ́

Daglig gräns nådd

Uppgradera din plan för att fortsätta använda AI-funktioner med högre dagliga gränser.

Jämför alla planer →