YOR 1 Krönikeboken Kapitel 6

1 Krönikeboken 6

YOR · Jämför · Ljud

1Àwọn ọmọ Lefi: 2Àwọn ọmọ Kohati: 3Àwọn ọmọ Amramu: 4Eleasari jẹ́ baba Finehasi, 5Abiṣua baba Bukki, 6Ussi baba Serahiah, 7Meraioti baba Amariah, 8Ahitubu baba Sadoku, 9Ahimasi baba Asariah, 10Johanani baba Asariah. Olúwa tí Solomoni kọ́ sí Jerusalẹmu). 11Asariah baba Amariah 12Ahitubu baba Sadoku. 13Ṣallumu baba Hilkiah, 14Asariah baba Seraiah, 15A kó Josadaki lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Juda àti Jerusalẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ Nebukadnessari. 16Àwọn ọmọ Lefi: 17Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: 18Àwọn ọmọ Kohati: 19Àwọn ọmọ Merari: 20Ti Gerṣoni: 21Joah ọmọkùnrin rẹ̀, 22Àwọn ìran ọmọ Kohati: 23Elkana ọmọkùnrin rẹ̀, 24Tahati ọmọkùnrin rẹ̀, Urieli ọmọkùnrin rẹ̀, 25Àwọn ìran ọmọ Elkana: 26Elkana ọmọ rẹ̀, Sofai ọmọ rẹ̀ 27Eliabu ọmọ rẹ̀, 28Àwọn ọmọ Samuẹli: 29Àwọn ìran ọmọ Merari: 30Ṣimea ọmọ rẹ̀, Haggiah ọmọ rẹ̀ 31Èyí ní àwọn ọkùnrin Dafidi tí a fi sí ìdí orin nínú ilé Olúwa lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sinmi níbẹ̀. 32Wọ́n jíṣẹ́ pẹ̀lú orin níwájú àgọ́ ìpàdé títí tí Solomoni fi kọ́ ilé Olúwa ní Jerusalẹmu. Wọ́n ṣe iṣẹ́ ìsìn wọn ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà tí a fi lélẹ̀ fún wọn. 33Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ó sìn pẹ̀lú ọmọ wọn. 34ọmọ Elkana, ọmọ Jerohamu, 35ọmọ Sufu, ọmọ Elkana, 36ọmọ Elkana, ọmọ Joẹli, 37ọmọ Tahati, ọmọ Asiri, 38ọmọ Isari, ọmọ Kohati, 39Hemani sì darapọ̀ mọ́ Asafu, ẹni tí o sìn ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀: 40ọmọ Mikaeli, ọmọ Baaseiah, 41ọmọ Etini, 42ọmọ Etani, ọmọ Simma, 43ọmọ Jahati, 44láti ìbákẹ́gbẹ́ wọn, àwọn ará Merari wà ní ọwọ́ òsì rẹ̀: 45ọmọ Haṣabiah, 46ọmọ Amisi, ọmọ Bani, 47ọmọ Mahili, 48Àwọn Lefi ẹgbẹ́ wọn ni wọn yan àwọn iṣẹ́ yòókù ti àgọ́ fún, èyí tí í ṣe ilé Ọlọ́run. 49Ṣùgbọ́n Aaroni àti àwọn ìran ọmọ rẹ̀ jẹ́ àwọn tí ó gbé ọrẹ kalẹ̀ lórí pẹpẹ ẹbọ sísun àti lórí pẹpẹ tùràrí ní ìbátan pẹ̀lú gbogbo ohun tí a ṣe ní Ibi Mímọ́ Jùlọ. Ṣíṣe ètùtù fún Israẹli, ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí Mose ìránṣẹ́ Ọlọ́run ti pàṣẹ. 50Wọ̀nyí ni àwọn ìránṣẹ́ Aaroni: 51Bukki ọmọ rẹ̀, 52Meraioti ọmọ rẹ̀, Amariah ọmọ rẹ̀, 53Sadoku ọmọ rẹ̀ 54Wọ̀nyí ni ibùgbé wọn tí a pín fún wọn gẹ́gẹ́ bí agbègbè wọn (tí a fi lé àwọn ìran ọmọ Aaroni lọ́wọ́ tí ó wá láti ẹ̀yà Kohati, nítorí kèké alákọ́kọ́ jẹ́ tiwọn). 55A fún wọn ní Hebroni ní Juda pẹ̀lú àyíká pápá oko tútù ilẹ̀ rẹ̀. 56Ṣùgbọ́n àwọn pápá àti ìletò tí ó yí ìlú ńlá náà ká ni a fi fún Kalebu ọmọ Jefunne. 57Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìran ọmọ Aaroni ni a fún ní Hebroni (ìlú ti ààbò), àti Libina, Jattiri, Eṣitemoa, 58Hileni, Debiri, 59Aṣani, Jutta àti Beti-Ṣemeṣi lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ rẹ̀. 60Àti láti inú ẹ̀yà Benjamini, a fún wọn ní Gibeoni, Geba, Alemeti àti Anatoti lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 61Ìyókù àwọn ìran ọmọ Kohati ní a pín ìlú mẹ́wàá fún láti àwọn ìdílé ní ti ààbọ̀ ẹ̀yà Manase. 62Àwọn ìran ọmọ Gerṣoni, sí ìdílé ni a pín ìlú mẹ́tàlá fún láti ẹ̀yà àwọn ẹ̀yà Isakari, Aṣeri àti Naftali, àti láti apá ẹ̀yà Manase tí ó wà ní Baṣani. 63Sebuluni àwọn ìran ọmọ Merari, ìdílé sí ìdílé, ní a pín ìlú méjìlá fún láti ẹ̀yà Reubeni, Gadi àti Sebuluni. 64Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ Israẹli fún àwọn ará Lefi ní ìlú wọ̀nyí pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 65Láti ẹ̀yà Juda, Simeoni àti Benjamini ni a pín ìlú tí a ti dárúkọ wọn sẹ́yìn fún. 66Lára àwọn ìdílé Kohati ni a fún ní ìlú láti ẹ̀yà Efraimu gẹ́gẹ́ bí ìlú agbègbè wọn. 67Ní òkè orílẹ̀-èdè Efraimu, a fún wọn ní Ṣekemu (ìlú ńlá ti ààbò), àti Geseri 68Jokimeamu, Beti-Horoni. 69Aijaloni àti Gati-Rimoni lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 70Pẹ̀lú láti apá ààbọ̀ ẹ̀yà Manase àwọn ọmọ Israẹli fún Aneri àti Bileamu lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn, fún ìyókù àwọn ìdílé Kohati. 71Àwọn ará Gerṣoni gbà nǹkan wọ̀nyí. 72Láti ẹ̀yà Isakari wọ́n gba Kedeṣi, Daberati 73Ramoti àti Anenu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 74Láti ẹ̀yà Aṣeri wọ́n gba Maṣali, Abdoni, 75Hukoki àti Rehobu lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 76Pẹ̀lú láti ẹ̀yà Naftali wọ́n gba Kedeṣi ní Galili, Hammoni àti Kiriataimu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 77Àwọn ará Merari (ìyókù àwọn ará Lefi) gbà nǹkan wọ̀nyí. 78Láti ẹ̀yà Reubeni rékọjá Jordani ìlà-oòrùn Jeriko wọ́n gba Beseri nínú aginjù Jahisa, 79Kedemoti àti Mefaati, lápapọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọn. 80Pẹ̀lú láti ẹ̀yà Gadi wọ́n gba Ramoti ní Gileadi Mahanaimu, 81Heṣboni àti Jaseri lápapọ̀ pẹ̀lú àwọn ilẹ̀ pápá oko tútù wọn.

Daglig gräns nådd

Uppgradera din plan för att fortsätta använda AI-funktioner med högre dagliga gränser.

Jämför alla planer →