YOR Псалми Poglavlje 35

Псалми 35

YOR · Uporedi · Audio

1Olúwa, gbógun ti àwọn tí ń gbóguntì mí; 2Di asà àti àpáta mú, 3Fa idà àti ọ̀kọ̀ yọ 4Kí wọn kí ó dààmú, 5Jẹ́ kí wọn dàbí ìyàngbò níwájú afẹ́fẹ́, Olúwa kí ó máa lé wọn kiri. 6Jẹ́ kí ọ̀nà wọn kí ó ṣókùnkùn, kí ó sì máa yọ́, Olúwa kí ó máa lépa wọn! 7Nítorí pé, ní àìnídìí ni wọ́n dẹ àwọ̀n wọn sílẹ̀ fún mi, 8Kí ìparun kí ó wá sí orí rẹ̀ ní òjijì. 9Nígbà náà ni ọkàn mi yóò yọ̀ nínú Olúwa, 10Gbogbo egungun mi yóò wí pé, Olúwa? 11Àwọn ẹlẹ́rìí èké dìde; 12Wọ́n fi búburú san ìre fún mi; 13Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi ni, nígbà tí wọn ń ṣe àìsàn, mo wọ aṣọ ọ̀fọ̀; 14èmí ń lọ kiri bí ẹni ń ṣọ̀fọ̀ 15Ṣùgbọ́n nínú ìkọ̀sẹ̀ mi wọ́n sì yọ̀, wọ́n sì kó ara wọn jọ; 16Bí àwọn àgàbàgebè tí ń ṣe ẹlẹ́yà ní àpèjẹ 17Yóò ti pẹ́ tó Olúwa, tí ìwọ yóò máa wò wọ́n lọ? 18Nígbà náà ni èmi yóò ṣọpẹ́ fún Ọ nínú àjọ ńlá; 19Má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi 20Nítorí pé wọn kò sọ ọ̀rọ̀ àlàáfíà, 21Wọ́n ya ẹnu wọn gbòòrò sí mi; wọ́n wí pé, “Háà! Háà! 22Ìwọ́ ti rí i Olúwa; má ṣe dákẹ́! 23Dìde! ru ara rẹ̀ sókè fún ààbò mi, 24Ṣe ìdájọ́ mi, Olúwa Ọlọ́run mi, gẹ́gẹ́ bí òdodo rẹ, 25Má ṣe jẹ́ kí wọn wí nínú ara wọn pé, “Háà! A ti rí ohun tí ọkàn wa ń fẹ́!” 26Kí ojú kí ó tì wọ́n, 27Jẹ́ kí àwọn tí ó fẹ́ ìdáláre mi Olúwa, 28Nígbà náà ni ahọ́n mi yóò máa sọ̀rọ̀ òdodo rẹ,