YOR Исаија Poglavlje 42

Исаија 42

YOR · Uporedi · Audio

1Ìránṣẹ́ mi nìyìí, ẹni tí mo gbéró, 2Òun kì yóò pariwo tàbí kígbe sókè, 3Koríko odò títẹ̀ kan ni òun kì yóò fọ́, 4òun kì yóò kọsẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni kò ní rẹ̀wẹ̀sì 5Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run wí 6“Èmi, Olúwa, ti pè ọ́ ní òdodo, 7láti la àwọn ojú tí ó fọ́, 8“Èmi ni Olúwa; orúkọ mi nìyìí! 9Kíyèsi i, àwọn nǹkan àtijọ́ ti wáyé, Olúwa 10Kọ orin tuntun sí Olúwa 11Jẹ́ kí aginjù àti àwọn ìlú rẹ̀ kí ó gbé ohùn wọn sókè; 12Jẹ́ kí wọn fi ògo fún Olúwa 13Olúwa yóò rìn jáde gẹ́gẹ́ bí i ọkùnrin alágbára, 14“Fún ìgbà pípẹ́ ni mo ti dákẹ́ jẹ́ẹ́, 15Èmi yóò sọ òkè ńlá àti kékeré di ahoro 16Èmi yóò tọ àwọn afọ́jú ní ọ̀nà tí wọn kò tí ì mọ̀, 17Ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé òrìṣà, 18“Gbọ́, ìwọ adití, 19Ta ló fọ́jú bí kò ṣe ìránṣẹ́ mi, Olúwa? 20Ẹ̀yin ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan, ṣùgbọ́n ẹ kò ṣe àkíyèsí; 21Ó dùn mọ́ Olúwa 22Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn kan nìyìí tí a jà lógun 23Ta ni nínú yín tí yóò tẹ́tí sí èyí 24Ta ni ó fi Jakọbu lélẹ̀ fún ìkógun, Olúwa ni, 25Nítorí náà ni ó ṣe rọ̀jò ìbínú un rẹ̀ lé wọn lórí,