YOR Псалми Poglavlje 37

Псалми 37

YOR · Uporedi · Audio

1Má ṣe ìkanra nítorí àwọn olùṣe búburú, 2nítorí pé wọn yóò gbẹ bí i koríko, 3Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa, kí o sì máa ṣe rere; 4Ṣe inú dídùn sí Olúwa; 5Fi ọ̀nà rẹ lé Olúwa lọ́wọ́; 6Yóò sì mú kí òdodo rẹ̀ jáde bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀, 7Ìwọ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Olúwa, 8Fàsẹ́yìn nínú inúbíbí, kí o sì kọ ìkáàánú sílẹ̀, 9Nítorí tí á ó gé àwọn olùṣe búburú kúrò, Olúwa àwọn ni yóò jogún ilẹ̀ náà. 10Síbẹ̀ nígbà díẹ̀ sí i, àwọn ènìyàn búburú kì yóò sí mọ̀; 11Ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́kàn tútù ni yóò jogún ilẹ̀ náà, 12Ènìyàn búburú di rìkíṣí sí olóòtítọ́, 13ṣùgbọ́n Olúwa rẹ́rìn-ín sí àwọn ènìyàn búburú, 14Ènìyàn búburú fa idà yọ, 15Idà wọn yóò wọ àyà wọn lọ, 16Ohun díẹ̀ tí olódodo ní, 17nítorí pé a óò ṣẹ́ ọwọ́ àwọn ènìyàn búburú, Olúwa gbé olódodo sókè. 18Olúwa mọ àwọn ọjọ́ àwọn tó dúró ṣinṣin, 19Ojú kì yóò tì wọ́n ní àkókò ibi, 20Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn búburú yóò ṣègbé. Olúwa yóò dàbí ẹwà oko tútù; 21Àwọn ènìyàn búburú yá, wọn kò sì san án padà, 22nítorí àwọn tí Olúwa bá bùkún ni yóò jogún ilẹ̀ náà, 23Ìlànà ìgbésẹ̀ ènìyàn rere wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá, 24bí ó tilẹ̀ ṣubú a kì yóò ta á nù pátápátá, Olúwa di ọwọ́ rẹ̀ mú. 25Èmi ti wà ni èwe, báyìí èmi sì dàgbà; 26Aláàánú ni òun nígbà gbogbo a máa yá ni; 27Lọ kúrò nínú ibi, kí o sì máa ṣe rere; 28Nítorí pé Olúwa fẹ́ràn ìdájọ́ òtítọ́, 29Olódodo ni yóò jogún ilẹ̀ náà, 30Ẹnu olódodo sọ̀rọ̀ ọgbọ́n, 31Òfin Ọlọ́run rẹ̀ ń bẹ ní àyà wọn; 32Ènìyàn búburú ń ṣọ́ olódodo, 33Olúwa kì yóò fi lé e lọ́wọ́ kì yóò sì dá a lẹ́bi, 34Dúró de Olúwa, 35Èmi ti rí ènìyàn búburú tí ń hu ìwà ìkà, 36ṣùgbọ́n ní ìṣẹ́jú kan sí i ó kọjá lọ, sì kíyèsi, kò sì sí mọ́; 37Máa kíyèsi ẹni pípé, kí o sì wo ẹni tó dúró ṣinṣin; 38Ṣùgbọ́n àwọn olùrékọjá ni a ó parun papọ̀; 39Ìgbàlà àwọn onídùúró ṣinṣin wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa; 40Olúwa yóò ràn wọ́n lọ́wọ́ yóò sì gbà wọ́n;