YOR Proverbs Kapitola 27

Proverbs 27

YOR · Porovnať · Audio

1Má ṣe yangàn nítorí ọ̀la 2Jẹ́ kí ẹlòmíràn yìn ọ́ dípò ẹnu ara rẹ, 3Òkúta wúwo, erùpẹ̀ sì wúwo 4Ìbínú ni ìkà, ìrunú sì burú púpọ̀ 5Ìbániwí gbangba sàn 6Òtítọ́ ni ọgbẹ́ ọ̀rẹ́, 7Kódà oyin kò dùn lẹ́nu ẹni tí ó ti yó 8Bí ẹyẹ tí ó ṣáko lọ kúrò níbi ìtẹ́ rẹ̀ 9Ìpara olóòórùn dídùn àti tùràrí ń mú ayọ̀ wá sínú ọkàn 10Má ṣe kọ ọ̀rẹ́ rẹ àti ọ̀rẹ́ baba rẹ sílẹ̀, 11Gbọ́n, ọmọ mi, kí o sì mú ayọ̀ wá sínú ọkàn mi 12Ọlọ́gbọ́n rí ewu, ó sì fi ara pamọ́ 13Gba aṣọ ẹni tí ó ṣe onídùúró fún àjèjì 14Bí ènìyàn kan ń kígbe súre fún aládùúgbò rẹ ní òwúrọ̀ 15Àyà tí ó máa ń jà dàbí 16dídá a lẹ́kun dàbí ìgbà tí ènìyàn ń dá afẹ́fẹ́ lẹ́kun 17Bí irin tí ń pọ́n irin mú 18Ẹni tí ó tọ́jú igi ọ̀pọ̀tọ́ yóò jẹ èso rẹ̀ 19Bí omi tí ń ṣe àfihàn ojú, nígbà tí a bá wò ó 20Kò tẹ́ ikú àti ìparun lọ́rùn rí 21Iná fún fàdákà iná ìléru fún wúrà, 22Bí a tilẹ̀ gún aláìgbọ́n nínú odó, 23Rí i dájú pé o mọ ipò tí àwọn agbo àgùntàn rẹ wà 24nítorí ọrọ̀ kì í pẹ́ lọ títí 25Nígbà tí a bá kó koríko, ewéko tuntun yóò sì hù jáde, a ó sì kó koríko àwọn orí òkè wọlé 26àwọn àgùntàn yóò pèsè aṣọ fún ọ, 27Ìwọ yóò ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ wàrà ewúrẹ́

Dosiahnutý dennýLimit

Upgradujte svoj balík, aby ste pokračovali v používaní funkcií AI s vyššími dennými limitmi.

Porovnať všetky plány →