YOR Joel Kapitola 3

Joel 3

YOR · Porovnať · Audio

1Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, àti ní àkókò náà, 2Èmi yóò kó gbogbo orílẹ̀-èdè jọ 3Wọ́n si ti di ìbò fún àwọn ènìyàn mi; 4“Nísinsin yìí, kí ni ẹ̀yin ní fi mí ṣe Tire àti Sidoni, àti gbogbo ẹ̀yin ẹkún Filistia? Ẹ̀yin yóò ha sàn ẹ̀san fún mi? Bí ẹ̀yin bá sì san ẹ̀san fún mi, ní kánkán àti ní kíákíá ní èmi yóò san ẹ̀san ohun ti ẹ̀yin ṣe padà sórí ara yín. 5Nítorí tí ẹ̀yin tí mú fàdákà mi àti wúrà mi, ẹ̀yin si tí mú ohun rere dáradára mi lọ sínú tẹmpili yín. 6Àti àwọn ọmọ Juda, àti àwọn ọmọ Jerusalẹmu ní ẹ̀yin ti tà fún àwọn ará Giriki, kí ẹ̀yin bá à lè sí wọn jìnnà kúrò ní agbègbè ilẹ̀ ìní wọn. 7“Kíyèsi í, èmi yóò gbé wọ́n dìde kúrò níbi tì ẹ̀yin ti tà wọ́n sí, èmi yóò sì san ẹ̀san ohun ti ẹ ṣe padà sórí ara yín. 8Èmi yóò si tà àwọn ọmọkùnrin yín àti àwọn ọmọbìnrin yín sí ọwọ́ àwọn ọmọ Juda, wọ́n yóò sì tà wọ́n fún àwọn ara Sabeani, fún orílẹ̀-èdè kan tí ó jìnnà réré.” Nítorí Olúwa ní o ti sọ ọ. 9Ẹ kéde èyí ní àárín àwọn kèfèrí; 10Ẹ fi irin ìtulẹ̀ yín rọ idà, 11Ẹ wá kánkán, gbogbo ẹ̀yin kèfèrí láti gbogbo àyíká, Olúwa. 12“Ẹ jí, ẹ sì gòkè wá sí àfonífojì 13Ẹ tẹ dòjé bọ̀ ọ́, 14Ọ̀pọ̀lọpọ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ Olúwa kù si dẹ̀dẹ̀ 15Oòrùn àti òṣùpá yóò ṣú òkùnkùn, 16Olúwa yóò sí ké ramúramù láti Sioni wá, Olúwa yóò ṣe ààbò àwọn ènìyàn rẹ̀, 17“Nígbà náà ni ẹ̀yin yóò mọ̀ pé, èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín, 18“Ní ọjọ́ náà, àwọn òkè ńlá yóò máa kán ọtí wáìnì tuntun sílẹ̀, Olúwa wá, 19Ṣùgbọ́n Ejibiti yóò di ahoro, 20Ṣùgbọ́n Juda yóò jẹ́ ibùgbé títí láé, 21Nítorí èmi yóò wẹ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ wọn nù, tí èmi kò tí ì wẹ̀nù. Olúwa ń gbé Sioni.”

Dosiahnutý dennýLimit

Upgradujte svoj balík, aby ste pokračovali v používaní funkcií AI s vyššími dennými limitmi.

Porovnať všetky plány →