Job 12
1Jobu sì dáhùn, ó sì wí pé, 2“Kò sí àní àní níbẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ̀yin ni àwọn ènìyàn náà, 3Ṣùgbọ́n èmi ní ìyè nínú gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin; 4“Èmi dàbí ẹni tí a ń fi ṣe ẹlẹ́yà lọ́dọ̀ aládùúgbò rẹ̀, 5Ó rọrùn fún ènìyàn láti fi ìbànújẹ́ ẹlòmíràn ṣe ẹlẹ́yà 6Àgọ́ àwọn ìgárá ọlọ́ṣà wá láìní ìbẹ̀rù; 7“Ṣùgbọ́n nísinsin yìí bí àwọn ẹranko léèrè, wọn o kọ́ ọ ní ẹ̀kọ́, 8Tàbí ba ilẹ̀ ayé sọ̀rọ̀, yóò sì kọ́ ọ, 9Ta ni kò mọ̀ nínú gbogbo nǹkan wọ̀nyí pé, Olúwa ni ó ṣe nǹkan yìí? 10Ní ọwọ́ ẹni tí ẹ̀mí ohun alààyè gbogbo gbé wà, 11Etí kì í dán ọ̀rọ̀ wò bí 12Àwọn arúgbó ni ọgbọ́n wà fún, 13“Ti Ọlọ́run ni ọgbọ́n àti agbára; 14Kíyèsi i, ó bì wó, a kò sì lè gbe ró mọ́; 15Kíyèsi i, ó dá àwọn omi dúró, wọ́n sì gbẹ; 16Tìrẹ ni agbára àti ìṣẹ́gun; 17Ó mú àwọn ìgbìmọ̀ lọ ní ìhòhò 18Ó tú ìdè ọba 19Ó mú àwọn àlùfáà lọ ní ìhòhò 20Ó mú ọ̀rọ̀ ẹnu ẹni ìgbẹ́kẹ̀lé kúrò 21Ó bu ẹ̀gàn lu àwọn ọmọ ọlọ́lá 22Ó hú ìdí ohun ìjìnlẹ̀ jáde láti inú òkùnkùn wá 23Òun a mú orílẹ̀-èdè bí sí i, a sì run wọ́n; 24Òun a gba òye àwọn olórí àwọn ènìyàn aráyé, 25Wọn a máa fi ọwọ́ ta ilẹ̀ nínú òkùnkùn níbi tí kò sí ìmọ́lẹ̀;