YOR Isaiah Kapitola 14

Isaiah 14

YOR · Porovnať · Audio

1Olúwa yóò fi àánú hàn fún Jakọbu, 2Àwọn orílẹ̀-èdè yóò gbà wọ́n Olúwa. 3Ní ọjọ́ tí Olúwa yóò fi ìtura fún un yín kúrò nínú ìpọ́njú àti ìyà àti ìdè ìkà, 4ẹ ó sì fi ọ̀rọ̀ àbùkù yìí kan ọba Babeli pé, 5Olúwa ti dá ọ̀pá ìkà náà, 6èyí tí ó ti lu àwọn ènìyàn bolẹ̀ 7Gbogbo ilẹ̀ ni ó wà ní ìsinmi àti àlàáfíà, 8Pẹ̀lúpẹ̀lú àwọn igi junifa àti àwọn 9Ibojì tí ó wà ní ìsàlẹ̀ ni a ru sókè 10Gbogbo wọn yóò dáhùn, 11Gbogbo rẹ̀ ni ó di ìrẹ̀sílẹ̀ lọ sí ibojì, 12Báwo ni ìwọ ṣe ṣubú lulẹ̀ láti ọ̀run wá, 13Ìwọ sọ nínú ọkàn rẹ pé, 14Èmi yóò gòkè lọ rékọjá àwọn àwọsánmọ̀; 15Ṣùgbọ́n a ti rẹ̀ ọ́ sílẹ̀ wọ inú ibojì lọ 16Àwọn tí ó rí ọ yóò tẹjúmọ́ ọ, 17Ẹni tí ó sọ ayé di aginjù, 18Gbogbo àwọn ọba orílẹ̀-èdè ni a tẹ́ sílẹ̀ 19Ṣùgbọ́n a jù ọ́ síta kúrò nínú ibojì 20a kò ní sin ọ́ pẹ̀lú wọn, 21Tọ́jú ibìkan tí a ó ti pa àwọn ọmọkùnrin rẹ 22“Èmi yóò dìde sókè sí wọn,” Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí. Olúwa wí. 23Èmi yóò yí i padà sí ibùgbé àwọn òwìwí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí. 24Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti búra, 25Èmi yóò run Asiria ní ilẹ̀ mi, 26Èyí ni ètò tí a pinnu rẹ̀ fún gbogbo ayé, 27Nítorí Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti pète, 28Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ yí wá ní ọdún tí ọba Ahasi kú. 29Má ṣe yọ̀, gbogbo ẹ̀yin Filistia, 30Ẹni tí ó kúṣẹ̀ẹ́ jù yóò ní pápá oko, 31Hu, ìwọ ẹnu-ọ̀nà! Kígbe, ìwọ ìlú! 32Kí ni ìdáhùn tí a ó fún Olúwa ti fi ìdí Sioni kalẹ̀,

Dosiahnutý dennýLimit

Upgradujte svoj balík, aby ste pokračovali v používaní funkcií AI s vyššími dennými limitmi.

Porovnať všetky plány →