Иов 24
1“Ṣe bí ìgbà kò pamọ́ lọ́dọ̀ Olódùmarè fún ìdájọ́? 2Wọ́n a sún àmì ààlà ilẹ̀, 3Wọ́n á sì da kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ aláìní baba lọ, 4Wọ́n á bi aláìní kúrò lójú ọ̀nà, 5Kíyèsi i, bí i kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó nínú ijù ni àwọn tálákà jáde lọ sí iṣẹ́ wọn, 6Olúkúlùkù a sì sá ọkà oúnjẹ ẹran rẹ̀ nínú oko, 7Ní ìhòhò ni wọn máa sùn láìní aṣọ, 8Ọ̀wààrà òjò òkè ńlá sì pa wọ́n, 9Wọ́n já ọmọ aláìní baba kúrò ní ẹnu ọmú, 10Wọ́n rìn kiri ní ìhòhò láìní aṣọ; 11Àwọn ẹni tí ń fún òróró nínú àgbàlá wọn, 12Àwọn ènìyàn ń kérora láti ìlú wá, 13“Àwọn ni ó wà nínú àwọn tí ó ṣọ̀tẹ̀ sí ìmọ́lẹ̀, 14Apànìyàn a dìde ní àfẹ̀mọ́júmọ́, 15Ojú alágbèrè pẹ̀lú dúró kí ilẹ̀ ṣú díẹ̀; 16Ní òkùnkùn wọn á rúnlẹ̀ wọlé, 17Nítorí pé bí òru dúdú ní òwúrọ̀ fún gbogbo wọn; 18“Ó yára lọ bí ẹni lójú omi; 19Gẹ́gẹ́ bi ọ̀dá àti òru ní í mú omi òjò-dídì yọ́, 20Inú ìbímọ yóò gbàgbé rẹ̀, 21Ẹni tí o hù ìwà búburú sí àgàn 22Ọlọ́run fi ipá agbára rẹ̀ fa alágbára, 23Ọlọ́run sì fi àìléwu fún un, 24A gbé wọn lékè nígbà díẹ̀, wọ́n kọjá lọ; 25“Ǹjẹ́, bí kò bá rí bẹ́ẹ̀ nísinsin yìí, ta ni yóò mú mi ní èké,