Иов 8
1Ìgbà náà ni Bilidadi, ará Ṣuhi, sì dáhùn wí pé, 2“Ìwọ yóò ti máa sọ nǹkan wọ̀nyí pẹ́ tó? 3Ọlọ́run a ha máa yí ìdájọ́ po bí? 4Nígbà tí àwọn ọmọ rẹ̀ ṣẹ̀ sí i, 5Bí ìwọ bá sì ké pe Ọlọ́run ní àkókò, 6Ìwọ ìbá jẹ́ mímọ, kí ó sì dúró ṣinṣin: 7Ìpilẹ̀ṣẹ̀ rẹ ìbá tilẹ̀ kéré si í, 8“Èmi bẹ̀ ọ́ ǹjẹ́, béèrè lọ́wọ́ àwọn ará ìgbà nì 9Nítorí pé ọmọ-àná ni àwa, a kò sì mọ nǹkan, 10Àwọn kì yóò wa kọ ọ́, wọn kì yóò sì sọ fún ọ? 11Papirusi ha lè dàgbà láìní ẹrẹ̀ 12Nígbà tí ó wà ní tútù, tí a kò ké e lulẹ̀, 13Bẹ́ẹ̀ ni ipa ọ̀nà gbogbo àwọn tí ó gbàgbé Ọlọ́run, 14Àbá ẹni tí a ó kèé kúrò, 15Yóò fi ara ti ilé rẹ̀, ṣùgbọ́n kì yóò lè dúró, 16Ó tutù bí irúgbìn tí a bomirin níwájú oòrùn, 17Gbòǹgbò rẹ̀ ta yí ebè ká, 18Bí ó bá sì pa á run kúrò ní ipò rẹ̀, 19Kíyèsi i, ayé rẹ̀ gbẹ dànù 20“Kíyèsi i, Ọlọ́run kì yóò ta ẹni òtítọ́ nù, 21títí yóò fi fi ẹ̀rín kún ọ ní ẹnu, 22ìtìjú ní a o fi bo àwọn tí ó kórìíra rẹ̀,