YOR Исаия Глава 41

Исаия 41

1Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú mi ẹ̀yin erékùṣù! 2“Ta ni ó ti ru ẹnìkan sókè láti ìlà-oòrùn wá, 3Ó ń lépa wọn ó sì ń kọjá ní àlàáfíà, 4Ta ni ó ti ṣe èyí tí ó sì ti jẹ́ kí ó wáyé, Olúwa pẹ̀lú ẹni kìn-ín-ní wọn 5Àwọn erékùṣù ti rí i wọ́n bẹ̀rù; 6èkínní ran èkejì lọ́wọ́ 7Oníṣọ̀nà gba alágbẹ̀dẹ wúrà níyànjú, 8“Ṣùgbọ́n ìwọ, ìwọ Israẹli, ìránṣẹ́ mi, 9mo mú ọ láti ìpẹ̀kun ilẹ̀ ayé, 10Nítorí náà má bẹ̀rù, nítorí èmi wà pẹ̀lú rẹ; 11“Gbogbo àwọn tí ó bínú sí ọ 12Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ yóò wá àwọn ọ̀tá rẹ, 13Nítorí Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ, 14Má ṣe bẹ̀rù, ìwọ Jakọbu kòkòrò, Olúwa wí, 15“Kíyèsi, Èmi yóò sọ ọ́ di òòlù ìpakà tuntun, 16Ìwọ yóò fẹ́ wọn, afẹ́fẹ́ yóò sì gbá wọn mú, Olúwa 17“Àwọn tálákà àti aláìní wá omi, Olúwa yóò dá wọn lóhùn; 18Èmi yóò mú kí odò kí ó sàn ní ibi gíga 19Èmi yóò fi sínú aṣálẹ̀ 20tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn ènìyàn yóò fi rí i tí wọn yóò sì fi mọ̀, Olúwa ni ó ti ṣe èyí, 21“Mú ẹjọ́ wá,” ni Olúwa wí. 22“Mú àwọn ère òrìṣà rẹ wọlé láti sọ fún wa 23ẹ sọ fún wa ohun ti ọjọ́ iwájú mú dání 24Ṣùgbọ́n ẹ̀yìn ko jásí nǹkan kan 25“Èmi ti ru ẹnìkan sókè láti àríwá, òun sì ń bọ 26Ta ni ó sọ èyí láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, tí àwa kò bá fi mọ̀, 27Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó sọ fún Sioni pé, ‘Wò ó, àwọn nìyìí!’ 28Èmi wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan— 29Kíyèsi i, irọ́ ni gbogbo wọn!

Дневной лимит достигнут

Обновите свой тариф, чтобы продолжить использовать функции ИИ с более высокими дневными лимитами.

Сравнить все тарифы →