YOR Амос Глава 1

Амос 1

1Àwọn ọ̀rọ̀ Amosi, ọ̀kan lára àwọn olùṣọ́-àgùntàn Tekoa; ohun tí o rí nípa Israẹli ní ọdún méjì ṣáájú ilẹ̀-rírì, nígbà tí Ussiah ọba Juda àti Jeroboamu ọmọ Jehoaṣi jẹ́ ọba ní ilẹ̀ Israẹli. 2Ó wí pé, Olúwa yóò bú jáde láti Sioni, 3Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 4Èmi yóò rán iná sí ilé Hasaeli, 5Èmi yóò ṣẹ́ ọ̀pá ìdábùú Damasku; Olúwa wí. 6Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 7Èmi yóò rán iná sí ara odi Gasa 8Èmi yóò ké àwọn olùgbé Aṣdodu kúrò, Olúwa Olódùmarè wí. 9Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 10Èmi yóò rán iná sí ara odi Tire, 11Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 12Èmi yóò rán iná sí orí Temani, 13Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 14Èmi yóò rán iná sí ara odi Rabba 15Ọba wọn yóò sì lọ sí ìgbèkùn, Olúwa wí.

Дневной лимит достигнут

Обновите свой тариф, чтобы продолжить использовать функции ИИ с более высокими дневными лимитами.

Сравнить все тарифы →