Provérbios 23
1Nígbà tí ìwọ bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun, 2Ìwọ a sì fi ọ̀bẹ lé ara rẹ ní ọ̀fun, 3Má ṣe fẹ́ oúnjẹ dídùn rẹ̀: 4Má ṣe ṣe làálàá láti lọ́rọ̀: 5Ìwọ ó ha fi ojú rẹ lépa ohun tí kò sí? 6Má ṣe jẹ oúnjẹ ẹni tí ó háwọ́, 7Nítorí pé bí ẹni tí ń ṣírò ní ọkàn rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ó rí: 8Òkèlè tí ìwọ jẹ ni ìwọ ó pọ̀ jáde, 9Má ṣe sọ̀rọ̀ ní etí aṣiwèrè; 10Má ṣe ṣí ààlà àtijọ́ kúrò; 11Nítorí pé Olùràpadà wọn lágbára; 12Fi àyà sí ẹ̀kọ́, 13Má ṣe fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kúrò lára ọmọdé, 14Bí ìwọ fi pàṣán nà án, 15Ọmọ mi, bí ọkàn rẹ bá gbọ́n, 16Inú mi yóò sì dùn nígbà tí ètè rẹ̀ bá ń sọ̀rọ̀ títọ́. 17Má ṣe jẹ́ kí àyà rẹ ó ṣe ìlara sí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, Olúwa, 18Nítorí pé ìgbẹ̀yìn ń bẹ nítòótọ́; 19Gbọ́, ìwọ ọmọ mi, kí o sì gbọ́n, 20Má ṣe wà nínú àwọn ọ̀mùtí; 21nítorí pé ọ̀mùtí àti ọ̀jẹun ni yóò di tálákà; 22Fetí sí ti baba rẹ tí ó bí ọ, 23Ra òtítọ́, kí o má sì ṣe tà á; 24Baba olódodo ni yóò yọ̀ gidigidi: 25Jẹ́ kí baba rẹ àti ìyá rẹ ó yọ̀, 26Ọmọ mi, fi àyà rẹ fún mi, 27Nítorí pé panṣágà obìnrin ọ̀gbun jíjìn ni; 28Òun á sì ba ní bùba bí olè, 29Ta ni ó ni òsì? Ta ni ó ni ìbànújẹ́? 30Àwọn tí ó dúró pẹ́ níbi ọtí wáìnì; 31Ìwọ má ṣe wò ọtí wáìnì nígbà tí ó pọ́n, 32Níkẹyìn òun á bu ni ṣán bí ejò, 33Ojú rẹ yóò wò àwọn àjèjì obìnrin, 34Nítòótọ́, ìwọ ó dàbí ẹni tí ó dùbúlẹ̀ ní àárín Òkun, 35Ìwọ ó sì wí pé, “Wọ́n lù mí; kò dùn mí;