Isaías 11
1Èèkàn kan yóò sọ láti ibi kùkùté Jese, 2Ẹ̀mí Olúwa yóò sì bà lé e, Olúwa. 3Òun yóò sì ní inú dídùn nínú ìbẹ̀rù Olúwa. 4ṣùgbọ́n pẹ̀lú òdodo ni yóò ṣe ìdájọ́ àwọn aláìní, 5Òdodo ni yóò jẹ́ ìgbànú rẹ̀ 6Ìkookò yóò sì máa bá ọmọ àgùntàn gbé, 7Màlúù àti beari yóò máa jẹun pọ̀, 8Ọ̀dọ́mọdé yóò ṣeré lẹ́bàá ihò ọká, 9Wọn kò ní ṣe ni léṣe tàbí pa ni run Olúwa 10Ní ọjọ́ náà, gbòǹgbò Jese yóò dúró gẹ́gẹ́ bí àsíá fún gbogbo ènìyàn, àwọn orílẹ̀-èdè yóò pagbo yí i ká, ibùdó ìsinmi rẹ̀ yóò jẹ́ èyí tí ó lógo. 11Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò na ọwọ́ rẹ̀ jáde nígbà kejì láti tún gba àwọn tí ó ṣẹ́kù àní àwọn tí a ṣẹ́kù nínú àwọn ènìyàn an rẹ̀ láti Asiria wá, láti ìsàlẹ̀ Ejibiti àti òkè Ejibiti, láti Kuṣi, láti Elamu láti Babiloni, láti Hamati àti láti àwọn erékùṣù inú Òkun. 12Òun yóò gbé àsíá sókè fún àwọn orílẹ̀-èdè, 13Owú jíjẹ Efraimu yóò pòórá, 14Wọn yóò fò mọ́ èjìká Filistini 15Olúwa yóò sọ di gbígbé 16Ọ̀nà gidi yóò wà fún àwọn ènìyàn an rẹ̀ tí ó ṣẹ́kù