YOR Êxodo Capítulo 15

Êxodo 15

YOR · Comparar · Áudio

1Nígbà náà ni Mose àti àwọn ọmọ Israẹli kọ orin yìí sí Olúwa, Olúwa, 2Olúwa ni agbára àti orin mi; 3Ológun ni Olúwa, Olúwa ni orúkọ rẹ, 4kẹ̀kẹ́ ogun Farao àti ogun rẹ̀ 5Ibú omi bò wọ́n mọ́lẹ̀; 6“Ọwọ́ ọ̀tún rẹ, Olúwa, Olúwa, 7“Nínú agbára ńlá rẹ ti ó tóbi 8Pẹ̀lú èémí imú rẹ ni 9Ọ̀tá ń gbéraga, ó ń wí pé, 10Ìwọ fẹ́ èémí rẹ, 11Ta ni nínú àwọn òrìṣà Olúwa? 12“Ìwọ na apá ọ̀tún rẹ, 13Nínú ìfẹ́ rẹ ti kì í sákí Ìwọ ṣe amọ̀nà 14Orílẹ̀-èdè yóò gbọ́ wọn yóò wárìrì. 15Ìbẹ̀rù yóò mú àwọn ìjòyè Edomu, 16Ìbẹ̀rù bojo yóò ṣubú lù wọ́n, nítorí Olúwa, 17Ìwọ yóò mú wọn wá láti gbìn wọ́n Olúwa. Olúwa. 18“Olúwa yóò jẹ ọba 19Nígbà ti ẹṣin Farao, kẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn ẹlẹ́ṣin rẹ̀ wọ inú Òkun, Olúwa mú kí omi òkun padà bò wọ́n mọ́lẹ̀, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Israẹli rìn lórí ìyàngbẹ ilẹ̀ la òkun kọjá. 20Miriamu wòlíì obìnrin, arábìnrin Aaroni, mú ohun èlò orin ni ọwọ́ rẹ̀, gbogbo àwọn obìnrin sì jáde tẹ̀lé e pẹ̀lú ìlù òun ijó. 21Miriamu kọrin sí wọn báyìí pé, Olúwa, 22Nígbà náà ni Mose ṣe amọ̀nà àwọn ènìyàn Israẹli jáde láti Òkun Pupa lọ sínú ijù Ṣuri. Wọ́n lọ ní ìrìn ọjọ́ mẹ́ta sínú ijù náà, wọn kò sì rí omi. 23Nígbà tí wọ́n dé Mara, wọn kò lè mu omi Mara nítorí omi náà korò. (Nítorí náà ni a ṣe pe ibẹ̀ ni Mara: ibi ìkorò.) 24Àwọn ènìyàn ń kùn sí Mose wí pé, “Kí ni àwa yóò mu?” 25Mose sì ké pe Olúwa, Olúwa sì fi igi kan hàn án, ó sì sọ igi náà sínú omi, omi náà sì dùn. Olúwa ti gbé ìlànà àti òfin kalẹ̀ fún wọn, níbẹ̀ ni ó sì ti dán wọn wò. 26Ó wí pé, “Bí ìwọ bá fetísílẹ̀ dáradára sí òfin Olúwa Ọlọ́run, ti ìwọ sì ṣe ohun tí ó tọ́ ni ojú rẹ̀, ti ìwọ sì tẹ̀lé ohun tí ó pàṣẹ, ti ìwọ si pa ìlànà rẹ̀ mọ́. Èmi kì yóò jẹ́ kí èyíkéyìí nínú àwọn ààrùn wọ̀n-ọn-nì ti mo mú wá sórí àwọn ará Ejibiti wá sí ara rẹ, nítorí Èmi ni Olúwa ti ó mú ọ láradá.” 27Nígbà ti wọ́n dé Elimu, níbi ti kànga omi méjìlá àti àádọ́rin ọ̀pẹ gbé wà, wọ́n pàgọ́ síbẹ̀ ni etí omi.

Limite Diário Atingido

Atualize seu plano para continuar usando recursos de IA com limites diários mais altos.

Comparar todos os planos →