YOR Isaías Capítulo 10

Isaías 10

YOR · Comparar · Áudio

1Ègbé ni fún àwọn ti ń ṣe òfin àìṣòdodo, 2láti dún àwọn aláìní ní ẹ̀tọ́ wọn 3Kí ni ìwọ yóò ṣe ní ọjọ́ ìṣirò 4Ohunkóhun kò ní ṣẹ́kù mọ́ bí kò ṣe láti tẹ̀ ba láàrín àwọn ìgbèkùn 5“Ègbé ni fún àwọn ará Asiria, ọ̀gọ ìbínú mi, 6Mo rán an sí orílẹ̀-èdè aláìní Ọlọ́run, 7Ṣùgbọ́n, èyí kì í ṣe ohun tí ó fẹ́ ṣe, 8‘Kì í ha ṣe pé ọba ni gbogbo àwọn aláṣẹ mi?’ ni Olúwa wí. 9‘Kì í ha ṣe pé Kalno dàbí i Karkemiṣi? 10Gẹ́gẹ́ bí ọwọ́ mi ti gbá ìjọba àwọn òrìṣà mú, 11Èmi kì yóò a bá Jerusalẹmu wí àti àwọn ère rẹ̀?’ ” 12Nígbà tí Olúwa ti ṣe iṣẹ́ rẹ̀ sí òkè Sioni àti Jerusalẹmu, yóò sọ wí pé, “Èmi yóò fi ìyà jẹ ọba Asiria nítorí gààrù àyà rẹ̀ àti ìgbéraga ojú rẹ̀. 13Nítorí ó sọ pé: 14Bí ènìyàn ti í tọwọ́ bọ ìtẹ́ ẹyẹ, 15Ǹjẹ́ àáké le gbé ara rẹ̀ sókè kọjá ẹni tí ó ń fì í, 16Nítorí náà, ni Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 17Ìmọ́lẹ̀ Israẹli yóò di iná, 18Gbogbo ẹwà igbó o rẹ̀, àti àwọn pápá ọlọ́ràá 19Àwọn igi tí yóò kù nínú igbó o rẹ̀ 20Ní ọjọ́ náà, àwọn tí ó ṣẹ́kù ní Israẹli, Olúwa, 21Àwọn ìyókù yóò padà, àwọn ìyókù ti Jakọbu 22Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ènìyàn rẹ, ìwọ Israẹli dàbí yanrìn ní Òkun, 23Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni yóò mú un ṣẹ, 24Nítorí náà, báyìí ni Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, 25Láìpẹ́, ìbínú mi sí i yín yóò wá sí òpin 26Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò nà wọ́n ní ẹgba. 27Ní ọjọ́ náà, a ó gbé ẹrù wọn kúrò ní èjìká a yín, 28Wọ́n wọ Aiati, 29Wọ́n ti rékọjá ọ̀nà, wọ́n wí pé, 30Gbé ohùn rẹ sókè, ìwọ ọmọbìnrin Galimu! 31Madmena ti fẹsẹ̀ fẹ́ ẹ, 32Ní ọjọ́ yìí, wọn yóò dúró ní Nobu 33Wò ó, Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 34Òun yóò gé igbó dídí pẹ̀lú àáké,

Limite Diário Atingido

Atualize seu plano para continuar usando recursos de IA com limites diários mais altos.

Comparar todos os planos →