Izajasza 17
1Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Damasku: 2Àwọn ìlú Aroeri ni a ó kọ̀sílẹ̀ 3Ìlú olódi ni yóò pòórá kúrò ní Efraimu, Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí. 4“Ní ọjọ́ náà ni ògo Jakọbu yóò sá; 5Yóò sì dàbí ìgbà tí olùkórè kó àwọn 6Síbẹ̀síbẹ̀ irúgbìn díẹ̀ yóò ṣẹ́kù, Olúwa wí, àní Ọlọ́run Israẹli. 7Ní ọjọ́ náà, àwọn ènìyàn yóò gbójú sókè sí Ẹlẹ́dàá wọn, 8Wọn kò ní wo àwọn pẹpẹ mọ́, 9Ní ọjọ́ náà àwọn ìlú alágbára rẹ̀, yóò dàbí ẹ̀ka ìkọ̀sílẹ̀, àti ẹ̀ka téńté òkè tí wọ́n fi sílẹ̀ nítorí àwọn ọmọ Israẹli. Gbogbo wọn yóò sì di ahoro. 10Nítorí ìwọ ti gbàgbé Ọlọ́run ìgbàlà rẹ; 11Nítorí náà, bí ẹ tilẹ̀ mú àṣàyàn igi tí ẹ sì gbin àjàrà tí ó ti òkèrè wá, 12Kíyèsi i, ìrunú àwọn orílẹ̀-èdè— 13Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ènìyàn ń bú 14Ní aginjù, ìpayà òjijì!