Amosa 9
1Mo rí Olúwa, ó dúró ní ẹ̀bá pẹpẹ, ó sì wí pé: 2Bí wọ́n tilẹ̀ wa ilẹ̀ lọ sí ipò òkú, 3Bí wọ́n tilẹ̀ fi ara wọn pamọ́ ni orí òkè Karmeli, 4Bí wọ́n tilẹ̀ lọ sí ìgbèkùn ní iwájú àwọn ọ̀tá wọn 5Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 6Òun ni ẹni tí ó kọ́ ìtẹ́ rẹ̀ nínú àwọn ọ̀run Olúwa ni orúkọ rẹ̀. 7“Àbá ẹ̀yin ọmọ Israẹli Olúwa wí. 8“Dájúdájú, ojú Olúwa Olódùmarè Olúwa wí. 9“Nítorí Èmi yóò pàṣẹ, 10Gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ láàrín àwọn ènìyàn mi 11“Ní ọjọ́ náà ní 12kí wọn le jogún ìyókù Edomu Olúwa, ẹni tí yóò ṣe nǹkan wọ̀nyí wí. 13“Ọjọ́ náà ń bọ,” ni Olúwa wí, 14Èmi yóò si tún mú ìgbèkùn Israẹli ènìyàn mi padà bọ̀. 15Èmi yóò gbin Israẹli sí orí ilẹ̀ rẹ̀. Olúwa Ọlọ́run rẹ wí.