YOR Hosea Hoofdstuk 9

Hosea 9

YOR · Vergelijken · Audio

1Má ṣe yọ̀, ìwọ Israẹli; 2Àwọn ilẹ̀ ìpakà àti ilé ìfun wáìnì kò ní fún àwọn ènìyàn lóúnjẹ 3Wọn kò ní ṣẹ́kù sí ilé Olúwa 4Wọn kò ní fi ọrẹ ohun mímu fún Olúwa. Olúwa. 5Kí ni ẹ̀yin ó ṣe ní ọjọ́ àjọ̀dún tí a yàn Olúwa? 6Bí wọ́n tilẹ̀ yọ́ kúrò lọ́wọ́ ìparun 7Àwọn ọjọ́ ìjìyà ń bọ̀; 8Wòlíì, papọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run, 9Wọ́n ti gbilẹ̀ nínú ìwà ìbàjẹ́ 10“Mo rí Israẹli bí èso àjàrà ní aginjù. 11Ògo Efraimu yóò fò lọ bí ẹyẹ 12Bí wọ́n tilẹ̀ tọ́ ọmọ dàgbà. 13Mo rí Efraimu bí ìlú Tire 14Fún wọn, Olúwa! 15“Nítorí gbogbo ìwà búburú tí wọ́n hù ní Gilgali, 16Efraimu ti rẹ̀ dànù 17Ọlọ́run mi yóò kọ̀ wọ́n sílẹ̀

Dagelijks limiet bereikt

Upgrade uw plan om AI-functies met hogere dagelijkse limieten te gebruiken.

Alle abonnementen vergelijken →