Micha 7
1Ègbé ni fún mi! 2Àwọn olódodo sì ti kúrò ní ilẹ̀ náà, 3Ọwọ́ wọn méjèèjì ti múra tán láti ṣe búburú; 4Ẹni tí ó sàn jùlọ nínú wọn sì dàbí ẹ̀gún, 5Ẹ má ṣe gba ọ̀rẹ́ kan gbọ́; 6Nítorí tí ọmọkùnrin kò bọ̀wọ̀ fún baba rẹ̀, 7Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi ní ìwòye ní ìrètí sí Olúwa, 8Má ṣe yọ̀ mí, ìwọ ọ̀tá mi. Olúwa yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ fún mi. 9Nítorí èmi ti dẹ́ṣẹ̀ sí i, Olúwa, 10Nígbà náà ni ọ̀tá mi yóò rí i Olúwa Ọlọ́run rẹ wà?” 11Ọjọ́ tí a ó mọ odi rẹ yóò dé, 12Ní ọjọ́ náà àwọn ènìyàn yóò wá sọ́dọ̀ rẹ 13Ilẹ̀ náà yóò di ahoro fún àwọn olùgbé inú rẹ̀, 14Fi ọ̀pá rẹ bọ́ àwọn ènìyàn, agbo ẹran ìní rẹ, 15“Bí i ọjọ́ tí ó jáde kúrò ní Ejibiti wá, 16Orílẹ̀-èdè yóò rí i, ojú yóò sì tì wọ́n, 17Wọn yóò lá erùpẹ̀ bí ejò, Olúwa Ọlọ́run wa, 18Ta ni Ọlọ́run bí rẹ̀, 19Òun yóò tún padà yọ́nú sí wa; 20Ìwọ yóò fi òtítọ́ hàn sí Jakọbu