YOR Prediker Hoofdstuk 10

Prediker 10

YOR · Vergelijken · Audio

1Gẹ́gẹ́ bí òkú eṣinṣin tí ń fún òróró ìkunra ní òórùn búburú, 2Ọkàn ọlọ́gbọ́n a máa ṣí sí ohun tí ó tọ̀nà, 3Kódà bí ó ti ṣe ń rìn láàrín ọ̀nà, 4Bí ìbínú alákòóso bá dìde lòdì sí ọ, 5Ohun ibi kan wà tí mo ti rí lábẹ́ oòrùn, 6A gbé aṣiwèrè sí ọ̀pọ̀ ipò tí ó ga jùlọ, 7Mo ti rí ẹrú lórí ẹṣin, 8Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́ kòtò, ó le è ṣubú sínú rẹ̀; 9Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbe òkúta le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn; 10Bí àáké bá kú 11Bí ejò bá ṣán ni kí a tó lo oògùn rẹ̀, 12Ọ̀rọ̀ tí ó wá láti ẹnu ọlọ́gbọ́n a máa ní oore-ọ̀fẹ́ 13Ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ́ òmùgọ̀; 14Wèrè a sì máa ṣàfikún ọ̀rọ̀. 15Iṣẹ́ aṣiwèrè a máa dá a lágara 16Ègbé ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ tí ọba ń ṣe ìránṣẹ́ rẹ̀ 17Ìbùkún ni fún ọ, ìwọ ilẹ̀ èyí tí ọba rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọlọ́lá, 18Bí ènìyàn bá ń lọ́ra, àjà ilé a máa jì 19Ẹ̀rín rínrín ni a ṣe àsè fún, 20Ma ṣe bú ọba, kódà nínú èrò rẹ,

Dagelijks limiet bereikt

Upgrade uw plan om AI-functies met hogere dagelijkse limieten te gebruiken.

Alle abonnementen vergelijken →