YOR Psalm Kapittel 33

Psalm 33

YOR · Sammenlign · Lyd

1 yọ̀ nínú Olúwa, ẹ̀yin olódodo; 2Ẹ yin Olúwa pẹ̀lú dùùrù; 3Ẹ kọ orin tuntun sí i; 4Nítorí pé ọ̀rọ̀ Olúwa dúró ṣinṣin, 5Ó fẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ́; Olúwa. 6Nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ Olúwa ni a ṣe dá àwọn ọ̀run, 7Ó kó àwọn omi òkun jọ gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó wà nínú ìgò; 8Jẹ́ kí gbogbo ayé kí ó bẹ̀rù Olúwa: 9Nítorí tí ó sọ̀rọ̀, ó sì ti rí bẹ́ẹ̀; 10Olúwa ti mú ìmọ̀ràn àwọn orílẹ̀-èdè wá sí asán; 11Ìgbìmọ̀ Olúwa dúró títí ayérayé, 12Ìbùkún ni fún orílẹ̀-èdè náà, Ọlọ́run ẹni tí Olúwa jẹ́ tirẹ̀, 13Olúwa wò láti ọ̀run wá; 14Níbi tí ó ti jókòó lórí ìtẹ́ 15ẹni tí ó ṣe àyà wọn bákan náà, 16A kò gba ọba kan là nípasẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ-ogun; 17Ohun asán ni ẹṣin fún ìṣẹ́gun; 18Wò ó, ojú Olúwa wà lára àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, 19Láti gba ọkàn wọn kúrò lọ́wọ́ ikú 20Ọkàn wa dúró de Olúwa; 21Ọkàn wa yọ̀ nínú rẹ̀, 22Kí àánú rẹ, Olúwa, kí ó wà lára wa,

Daglig grense nådd

Oppgrader planen din for å fortsette å bruke AI-funksjoner med høyere daglige grenser.

Sammenlign alle planer →