YOR Zephaniah Kapittel 1

Zephaniah 1

YOR · Sammenlign · Lyd

1̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Sefaniah ọmọ Kuṣi, ọmọ Gedaliah, ọmọ Amariah, ọmọ Hesekiah, ní ìgbà Josiah ọmọ Amoni ọba Juda. 2“Èmi yóò mú gbogbo nǹkan kúrò Olúwa wí. 3“Èmi yóò mú ènìyàn àti ẹranko kúrò; Olúwa wí. 4“Èmi yóò na ọwọ́ mi sórí Juda 5àti àwọn tí ń foríbalẹ̀ lórí òrùlé, Olúwa búra, 6Àwọn tí ó yípadà kúrò lọ́dọ̀ Olúwa; Olúwa, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò sì béèrè rẹ̀.” 7Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Olúwa Olódùmarè, Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀. Olúwa ti pèsè ẹbọ kan sílẹ̀, 8“Ní ọjọ́ ẹbọ Olúwa, 9Ní ọjọ́ náà, èmi yóò fi ìyà jẹ 10“Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí, 11Ẹ hu, ẹ̀yin tí ń gbé ní agbègbè ọjà, 12Ní àkókò wọ̀n-ọn-nì, èmi yóò wá Jerusalẹmu kiri pẹ̀lú fìtílà, Olúwa kì yóò ṣe nǹkan kan 13Nítorí náà, ọrọ̀ wọn yóò di ìkógun, Olúwa 14“Ọjọ́ ńlá Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀, Olúwa yóò korò púpọ̀, 15ọjọ́ náà yóò jẹ́ ọjọ́ ìbínú, 16ọjọ́ ìpè àti ìpè ogun 17“Èmi yóò sì mú ìpọ́njú wá sórí ènìyàn, Olúwa. 18Bẹ́ẹ̀ ni fàdákà tàbí wúrà wọn Olúwa.”

Daglig grense nådd

Oppgrader planen din for å fortsette å bruke AI-funksjoner med høyere daglige grenser.

Sammenlign alle planer →