YOR Nahum Kapittel 3

Nahum 3

YOR · Sammenlign · Lyd

1Ègbé ni fún ìlú ẹ̀jẹ̀ nì, 2Ariwo pàṣán àti ariwo 3Ológun orí ẹṣin ń fi ìgbónára 4Nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ panṣágà 5“Èmi dojúkọ ọ́,” ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí. 6Èmi yóò da ẹ̀gbin tí ó ni ìríra sí ọ ní ara, 7Gbogbo àwọn tí ó ba sì wò ọ́ yóò sì káàánú fún ọ, wọn yóò sì wí pé, 8Ǹjẹ́ ìwọ ha sàn ju Tebesi lọ, 9Etiopia àti Ejibiti ni agbára rẹ, kò sí ní òpin; 10Síbẹ̀síbẹ̀ a kó o ní ìgbèkùn 11Ìwọ pẹ̀lú yóò sì mu àmupara; 12Gbogbo ilé ìṣọ́ agbára rẹ yóò dàbí igi ọ̀pọ̀tọ́ 13Kíyèsi gbogbo àwọn jagunjagun! 14Pọn omi nítorí ìhámọ́, 15Níbẹ̀ ni iná yóò ti jó ọ́ run; 16Ìwọ ti sọ àwọn oníṣòwò rẹ di púpọ̀ 17Àwọn aládé rẹ̀ dàbí eṣú, 18Ìwọ ọba Asiria, 19Kò sì sí ohun tí ó lè wo ọgbẹ́ ẹ̀ rẹ sàn;

Daglig grense nådd

Oppgrader planen din for å fortsette å bruke AI-funksjoner med høyere daglige grenser.

Sammenlign alle planer →