YOR Micah Pasal 1

Micah 1

YOR · Bandingkan · Audio

1̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Mika ará Moreṣeti wá ní àkókò ìjọba Jotamu, Ahasi, àti Hesekiah, àwọn ọba Juda nìwọ̀nyí, ìran tí ó rí nípa Samaria àti Jerusalẹmu. 2Ẹ gbọ́, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn, Olúwa Olódùmarè lè ṣe ẹlẹ́rìí sí yín, 3Wò ó! Olúwa ń bọ̀ wá láti ibùgbé rẹ̀; 4Àwọn òkè ńlá yóò sí yọ́ lábẹ́ rẹ̀, 5Nítorí ìré-òfin-kọjá Jakọbu ni gbogbo èyí, 6“Nítorí náà, èmi yóò ṣe Samaria bí òkìtì lórí pápá, 7Gbogbo àwọn ère fínfín rẹ̀ ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́ 8Nítorí èyí, èmi yóò sì sọkún, 9Nítorí tí ọgbẹ́ rẹ̀ jẹ́ aláìlèwòtán; 10Ẹ má ṣe sọ ní Gati 11Ẹ kọjá lọ ni ìhòhò àti ni ìtìjú, 12Nítorí àwọn tí ó ń gbé ni Marati ń retí ìre, Olúwa wá sí ẹnu-bodè Jerusalẹmu. 13Ìwọ olùgbé Lakiṣi, 14Nítorí náà ni ìwọ ó ṣe fi ìwé ìkọ̀sílẹ̀ 15Èmi yóò sì mú àrólé kan wá sórí rẹ ìwọ olùgbé Meraṣa. 16Fá irun orí rẹ nínú ọ̀fọ̀

Had Harian Dicapai

Tingkatkan pelan anda untuk terus menggunakan ciri AI dengan had harian yang lebih tinggi.

Bandingkan semua pelan →