YOR Amos Pasal 2

Amos 2

YOR · Bandingkan · Audio

1Èyí ni ohun tí Olúwa wí, 2Èmi yóò rán iná sí orí Moabu 3Èmi yóò ké onídàájọ́ rẹ̀ kúrò, Olúwa wí. 4Èyí ni ohun tí Olúwa wí, Olúwa sílẹ̀, 5Èmi yóò rán iná sí orí Juda 6Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 7Wọ́n fi ẹsẹ̀ tẹ orí àwọn tálákà mọ́lẹ̀, 8Wọ́n dùbúlẹ̀ lẹ́bàá a pẹpẹ, 9“Mo pa àwọn ará Amori run níwájú wọn 10Èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Ejibiti wá, 11“Èmi sì tún gbé àwọn wòlíì dìde láàrín àwọn ọmọ yín Olúwa wí. 12“Ṣùgbọ́n ẹ̀yin fún àwọn Nasiri ní ọtí mu 13“Ní báyìí, èmi yóò tẹ̀ yín mọ́lẹ̀ 14Ẹni tí ó yára bí àṣá kò ní rí ọ̀nà àbáyọ 15Tafàtafà kì yóò dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀ 16Àní jagunjagun tí ó gbóyà jùlọ Olúwa wí.

Had Harian Dicapai

Tingkatkan pelan anda untuk terus menggunakan ciri AI dengan had harian yang lebih tinggi.

Bandingkan semua pelan →