YOR 호세아 장 11

호세아 11

YOR · 비교 · 오디오

1Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọdé mo fẹ́ràn rẹ̀, 2Bí a ti ń pe wọn, 3Lóòtítọ́ mo kọ́ Efraimu pẹ̀lú ní ìrìn 4Mo fi okùn ènìyàn fà wọ́n 5“Ṣé wọn ò wá ní padà sí Ejibiti bí. 6Idà yóò kọ mọ̀nà ní gbogbo ìlú wọn 7Àwọn ènìyàn mi ti pinnu láti pẹ̀yìndà kúrò lọ́dọ̀ mi 8“Báwo ni èmi ó ṣe fi ọ́ sílẹ̀, Efraimu? 9Èmi kò ni mú ìbínú gbígbóná mi ṣẹ, 10Wọn yóò máa tẹ̀lé Olúwa; 11Wọn ó wá pẹ̀lú ẹ̀rù Olúwa wí. 12Efraimu tí fi irọ́ yí mi ká

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →