YOR 예레미야 애가 장 5

예레미야 애가 5

YOR · 비교 · 오디오

1Rántí, Olúwa, ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí wa; 2Àwọn ohun ìní wa ti di ti àlejò, 3Àwa ti di aláìní òbí àti aláìní baba, 4A gbọdọ̀ ra omi tí à ń mu; 5Àwọn tí ó ń lé wa súnmọ́ wa; 6Àwa jọ̀wọ́ ara wa fún Ejibiti àti Asiria 7Àwọn baba wa ti ṣẹ̀, wọn kò sì ṣí mọ́, 8Àwọn ẹrú ń jẹ ọba lórí wa, 9Àwa ń rí oúnjẹ wa nínú ewu ẹ̀mí wa 10Ẹran-ara wa gbóná bí ààrò, 11Wọ́n ti fipá bá àwọn obìnrin wa lòpọ̀ ní Sioni, 12Àwọn ọmọ ọbakùnrin ti di síso sókè ní ọwọ́ wọn; 13Àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin wa ru òkúta; 14Àwọn àgbàgbà ti lọ kúrò ní ẹnu-bodè ìlú; 15Ayọ̀ ti ṣáko ní ọkàn wa; 16Adé ti ṣí kúrò ní orí wa 17Nítorí èyí, àárẹ̀ mú ọkàn wa, 18Fún òkè Sioni tí ó ti di ahoro 19Ìwọ, Olúwa, jẹ ọba títí láé; 20Kí ló dé tí o ń gbàgbé wa ní gbogbo ìgbà? 21Mú wa padà sí ọ̀dọ̀ rẹ, Olúwa, kí àwa kí ó le padà; 22àyàfi tí o bá ti kọ̀ wá sílẹ̀ pátápátá

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →