YOR 아가 장 1

아가 1

YOR · 비교 · 오디오

1Orin, àwọn orin tí í ṣe orin Solomoni. 2Fi ìfẹnukonu ìfẹ́ kò mí ní ẹnu, 3Òórùn ìkunra rẹ fanimọ́ra. 4Fà mí lọ pẹ̀lú rẹ, kí a lọ kíákíá 5Èmi dúdú mo sì ní ẹwà. 6Má ṣe wò mí nítorí wí pé mo dúdú, 7Wí fún mi, ìwọ ẹni tí ọkàn mí fẹ́, 8Bí ìwọ kò bá mọ̀, 9Olùfẹ́ mi, 10Ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ dára ní ohun ọ̀ṣọ́, 11A ó fi wúrà ṣe òrùka etí fún ọ, 12Nígbà tí ọba wà ní orí ìjókòó rẹ̀, 13Ìdì òjìá ni olùfẹ́ mi jẹ sí mi, 14Bí ìdì ìtànná Henina ni olùfẹ́ mi rí sí mi 15Báwo ni o ti lẹ́wà tó, olólùfẹ́ mi! 16Báwo ni o ṣe dára tó, olùfẹ́ mi! 17Ìtànṣán ilé wa jẹ́ ti igi kedari

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →