YOR 아모스 장 4

아모스 4

YOR · 비교 · 오디오

1 gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin màlúù Baṣani lórí òkè Samaria, 2Olúwa Olódùmarè ti fi ìwà mímọ́ rẹ̀ búra: 3Ẹni kọ̀ọ̀kan yín yóò jáde lọ Olúwa wí. 4“Ẹ lọ sí Beteli láti dẹ́ṣẹ̀; 5Kí ẹ mú ọ̀rẹ́ ìdúpẹ́ ìyẹ̀fun ìwúkàrà ti a sun Olúwa Olódùmarè wí. 6“Èmi fún un yín ní mímọ́ eyín ní gbogbo ìlú yín, Olúwa wí. 7“Àti pẹ̀lú mo mú òjò dúró 8Àwọn ènìyàn ń rìn láti ìlú kan sí ìlú mìíràn fún omi Olúwa wí. 9“Lọ́pọ̀ ìgbà ni mo kọlu ọgbà àti ọgbà àjàrà yín Olúwa wí. 10“Mo rán àjàkálẹ̀-ààrùn sí i yín Olúwa wí. 11“Mo ti bì ṣubú nínú yín, Olúwa wí. 12“Nítorí náà, èyí ni ohun tí èmi yóò ṣe sí i yín, Israẹli, 13Ẹni tí ó dá àwọn òkè Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀.

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →