YOR Micah 章 6

Micah 6

YOR · 比較 · 音声

1 fi etí sí ohun tí Olúwa wí: 2“Gbọ́, ìwọ òkè ńlá, ẹ̀sùn Olúwa; Olúwa ń bá àwọn ènìyàn rẹ̀ wíjọ́; 3“Ẹ̀yin ènìyàn mi, kí ni mo ṣe fún yín? 4Nítorí èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Ejibiti wá, 5Ìwọ ènìyàn mi, Olúwa.” 6Kí ni èmi yóò ha mú wá síwájú Olúwa 7Ǹjẹ́ Olúwa yóò ní inú dídùn sí ẹgbẹgbàarùn-ún àgbò, 8Ó ti fihàn ọ́, ìwọ ènìyàn, ohun tí ó dára, Olúwa ń béèrè lọ́wọ́ rẹ? 9Gbọ́! Ohùn Olúwa kígbe sí ìlú ńlá náà, 10Ǹjẹ́ ìṣúra ìwà búburú ha wà 11Ǹjẹ́ èmi ha lè kà wọ́n sí mímọ́ 12Àwọn ọlọ́rọ̀ inú rẹ̀ kún fún ìwà ipá; 13Nítorí náà ni èmi yóò ṣe mú ọ ṣàìsàn ní lílù ọ́, 14Ìwọ yóò jẹun ṣùgbọ́n kì yóò yó; 15Ìwọ yóò gbìn ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò kórè 16Nítorí tí ìwọ ti pa òfin Omri mọ́,

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →