YOR Job 章 15

Job 15

YOR · 比較 · 音声

1Ìgbà náà ní Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé, 2“Ọlọ́gbọ́n a máa sọ̀rọ̀ ìmọ̀ asán 3Òun lè máa fi àròyé sọ̀rọ̀ tí kò ní èrè, 4Ṣùgbọ́n ìwọ ṣá ìbẹ̀rù tì, 5Nítorí pé ẹnu ara rẹ̀ ni ó jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, 6Ẹnu ara rẹ̀ ni ó dá lẹ́bi, kì í ṣe èmi; 7“Ìwọ ha í ṣe ọkùnrin tí a kọ́ bí? 8Ìwọ gbúròó àṣírí Ọlọ́run rí? 9Kí ni ìwọ mọ̀ tí àwa kò mọ̀? 10Àwọn arúgbó àti ògbólógbòó ènìyàn wà pẹ̀lú wa, 11Ìtùnú Ọlọ́run ha kéré lọ́dọ̀ rẹ? 12Èéṣe ti ọkàn rẹ fi ń ti ọ kiri, 13Tí ìwọ fi yí ẹ̀mí rẹ padà lòdì sí Ọlọ́run, 14“Kí ni ènìyàn tí ó fi jẹ mímọ́, 15Kíyèsi i, bi Ọlọ́run ko ba gbẹ́kẹ̀lé àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀, 16mélòó mélòó ni ènìyàn, ẹni ìríra àti eléèérí, 17“Èmi ó fihàn ọ́, gbọ́ ti èmi; 18ohun tí àwọn ọlọ́gbọ́n ti pa ní ìtàn láti 19Àwọn tí a fi ilẹ̀ ayé fún nìkan, 20Ènìyàn búburú ń ṣe làálàá, 21Ìró ìbẹ̀rù ń bẹ ní etí rẹ̀; 22Kò gbàgbọ́ pé òun ó jáde kúrò nínú òkùnkùn; 23Ó ń wò káàkiri fún oúnjẹ wí pé, níbo ní ó wà? 24Ìpọ́njú pẹ̀lú ìrora ọkàn yóò mú un bẹ̀rù, 25Nítorí pé ó ti nawọ́ rẹ̀ jáde lòdì sí Ọlọ́run, 26ó súre, ó sì fi ẹ̀yìn gíga, 27“Nítorí tí òun fi ọ̀rá rẹ̀ bo ara rẹ̀ lójú, 28Òun sì gbé inú ahoro ìlú, 29Òun kò lé di ọlọ́rọ̀, bẹ́ẹ̀ ohun ìní rẹ̀ kò 30Òun kì yóò jáde kúrò nínú òkùnkùn; 31Kí òun kí ó má ṣe gbẹ́kẹ̀lé asán, kí ó má sì ṣe tan ara rẹ̀ jẹ. 32A ó mú un ṣẹ ṣáájú pípé ọjọ́ rẹ̀, 33Yóò dàbí àjàrà tí a gbọn èso àìpọ́n rẹ̀ dànù, 34Nítorí pé ayọ̀ àwọn àgàbàgebè yóò túká, 35Wọ́n lóyún ìwà ìkà, wọ́n sì bí ẹ̀ṣẹ̀,

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →