YOR Job 章 22

Job 22

YOR · 比較 · 音声

1Ìgbà náà ni Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé, 2“Ènìyàn lè è ṣe rere fún Ọlọ́run? 3Ohun ayọ̀ ha ni fún Olódùmarè pé olódodo ni ìwọ? 4“Yóò ha bá ọ wí bí, nítorí ìbẹ̀rù 5Ìwà búburú rẹ kò ha tóbi, 6Nítòótọ́ ìwọ béèrè fún ààbò ni ọwọ́ arákùnrin rẹ láìnídìí, 7Ìwọ kò fi omi fún aláàárẹ̀ mu, 8Bí ó ṣe ti alágbára nì, òun ni ó ní ilẹ̀, 9Ìwọ ti rán àwọn opó padà lọ ní ọwọ́ òfo, 10Nítorí náà ni ìdẹ̀kùn ṣe yí ọ káàkiri, 11Èéṣe tí òkùnkùn fi pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ìwọ kò fi lè ríran. 12“Ọlọ́run kò ha jẹ́ ẹni gíga ọ̀run? 13Ìwọ sì wí pé, Ọlọ́run ti ṣe mọ̀? 14Ǹjẹ́ àwọsánmọ̀ tí ó nípọn jẹ ìbora fún un, 15Ǹjẹ́ ìwọ fẹ́ rin ipa ọ̀nà ìgbàanì tí àwọn 16A ké wọn lulẹ̀ kúrò nínú ayé láìpé ọjọ́ wọn, 17Àwọn ẹni tí ó wí fún Ọlọ́run pé, ‘Lọ kúrò lọ́dọ̀ wa! 18Síbẹ̀ ó fi ohun rere kún ilé wọn! 19Àwọn olódodo rí ìparun wọn, wọ́n sì yọ̀, 20‘Lóòtítọ́ àwọn ọ̀tá wa ni a ké kúrò, 21“Fa ara rẹ súnmọ́ Ọlọ́run, ìwọ ó sì rí àlàáfíà; 22Èmi bẹ̀ ọ́, gba òfin láti ẹnu rẹ̀ wá, 23Bí ìwọ bá yípadà sọ́dọ̀ Olódùmarè, a sì gbé ọ ró. 24tí ìwọ bá tẹ́ wúrà dáradára sílẹ̀, 25nígbà náà ní Olódùmarè yóò jẹ́ wúrà rẹ, 26Lóòtítọ́ nígbà náà ní ìwọ ó ní inú dídùn nínú Olódùmarè, 27Bí ìwọ bá gbàdúrà rẹ sọ́dọ̀ rẹ̀, yóò sì gbọ́ tìrẹ, 28Ìwọ ó sì gbìmọ̀ ohun kan pẹ̀lú, yóò sì fi ìdí múlẹ̀ fún ọ; 29Nígbà tí ipa ọ̀nà rẹ bá lọ sísàlẹ̀, 30Yóò gba ẹni tí kì í ṣe aláìjẹ̀bi là,

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →