YOR Song of Solomon 章 7

Song of Solomon 7

YOR · 比較 · 音声

1Báwo ni ẹsẹ̀ rẹ ti ní ẹwà tó nínú bàtà. 2Ìdodo rẹ rí bí àwo 3Ọmú rẹ rí bí abo egbin méjì 4Ọrùn rẹ rí bí ilé ìṣọ́ eyín erin. 5Bí òkè Karmeli ṣe ṣe adé yí àwọn òkè ká, 6Báwo ni ẹwà rẹ ti pọ̀ tó 7Ìdúró rẹ rí bí igi ọ̀pẹ, 8Mo ní, “Èmi yóò gun igi ọ̀pẹ lọ, 9Àti ìfẹnukonu rẹ rí bí ọtí wáìnì tí ó dára jùlọ. 10Ti olùfẹ́ mi ni èmi í ṣe, 11Wá, olùfẹ́ mi, jẹ́ kí a lọ sí ibi pápá, 12Jẹ́ kí a lọ sínú ọgbà àjàrà ní kùtùkùtù 13Àwọn èso mándrákì mú òórùn wọn jáde

1日の制限に達しました

プランをアップグレードして、より高い1日の制限でAI機能を使い続けてください。

すべてのプランを比較 →