Zaccaria 10
1Ẹ béèrè òjò nígbà àrọ̀kúrò ni ọwọ́ Olúwa; Olúwa tí o dá mọ̀nàmọ́ná, 2Nítorí àwọn òrìṣà tí sọ̀rọ̀ asán, 3“Ìbínú mi ru sí àwọn darandaran, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti bẹ agbo rẹ̀, 4Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni òkúta igun ilé ti jáde wá, 5Gbogbo wọn yóò sì dàbí ọkùnrin Olúwa wà pẹ̀lú wọn, 6“Èmi o sì mú ilé Juda ní agbára, Olúwa Ọlọ́run wọn, 7Efraimu yóò sì ṣe bí alágbára, Olúwa. 8Èmi ó kọ sí wọn, èmi ó sì ṣà wọ́n jọ; 9Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo tú wọn káàkiri orílẹ̀-èdè: 10Èmi ó sì tún mú wọn padà kúrò ni ilẹ̀ Ejibiti pẹ̀lú, 11Wọn yóò sì la Òkun wàhálà já, 12Èmi ó sì mú wọn ní agbára nínú Olúwa; Olúwa wí.