Proverbi 11
1Olúwa kórìíra òsùwọ̀n èké, 2Nígbà tí ìgbéraga bá dé, nígbà náà ni ìdójútì dé, 3Òtítọ́ inú ẹni dídúró ṣinṣin ń ṣe amọ̀nà rẹ̀, 4Ọ̀rọ̀ kò níláárí ní ọjọ́ ìbínú, 5Òdodo aláìlẹ́gàn ṣe ọ̀nà tààrà fún wọn, 6Òdodo ẹni ìdúró ṣinṣin gbà wọ́n là, 7Nígbà tí ènìyàn búburú bá kú, ìrètí rẹ̀ a parun; 8A gba olódodo kúrò lọ́wọ́ ibi dípò o rẹ̀, 9Aláìmọ Ọlọ́run fi ẹnu rẹ̀ ba aládùúgbò rẹ̀ jẹ́, 10Nígbà tí olódodo ń gbèrú, ìlú a yọ̀; 11Nípasẹ̀ ìbùkún, olódodo a gbé ìlú ga: 12Ẹni tí kò gbọ́n fojú kékeré wo aládùúgbò rẹ̀ 13Olófòófó tú àṣírí ìkọ̀kọ̀ 14Nítorí àìní ìtọ́sọ́nà orílẹ̀-èdè ṣubú 15Ẹni tí ó ṣe onígbọ̀wọ́ fún àlejò yóò rí ìyọnu, 16Obìnrin oníwà rere gba ìyìn 17Ènìyàn rere ń ṣe ara rẹ̀ lóore 18Ènìyàn búburú gba èrè ìtànjẹ 19Olódodo tòótọ́ rí ìyè 20Olúwa kórìíra àwọn ènìyàn ọlọ́kàn búburú 21Mọ èyí dájú pé, ènìyàn búburú kì yóò lọ láìjìyà, 22Bí òrùka wúrà ní imú ẹlẹ́dẹ̀ 23Ìfẹ́ inú olódodo yóò yọrí sí ohun rere 24Ènìyàn kan ń fún ni lọ́fẹ̀ẹ́, síbẹ̀ ó ń ní sí i; 25Ẹni tí ń ṣoore yóò máa gbèrú sí i; 26Àwọn ènìyàn a ṣẹ́ èpè lé ènìyàn tí ń kó oúnjẹ pamọ́ 27Ẹni tí ń lépa ohun rere yóò rí ohun rere 28Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ rẹ̀ yóò ṣubú; 29Ẹni tí ó ń mú ìdààmú dé bá ìdílé rẹ̀ yóò jogún afẹ́fẹ́ lásán 30Èso òdodo ni igi ìyè 31Bí àwọn olódodo bá gba ìpín wọn lórí ilẹ̀ ayé