Naum 1
1Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ nípa Ninefe. Ìwé ìran Nahumu ará Elkoṣi. Olúwa sí Ninefe 2Ọlọ́run ń jẹ owú, ó sì ń gbẹ̀san, Olúwa ń gbẹ̀san, ó sì kún fún ìbínú. Olúwa ń gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀. 3Olúwa lọ́ra láti bínú, ó sì tóbi ní agbára; Olúwa kì yóò fi àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ sílẹ̀ láìjìyà. 4Ó bá òkun wí, ó sì mú kí ó gbẹ; 5Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀, 6Ta ni ó lé dúró níwájú ìbínú rẹ̀? 7Rere ni Olúwa, 8ṣùgbọ́n pẹ̀lú ìkún omi ńlá 9Kí ni ẹ̀yìn ń gbìmọ̀ lòdì sí Olúwa? 10Wọn yóò sì lọ́lù papọ̀ bí ẹ̀gún òṣùṣú 11Láti ọ̀dọ̀ rẹ, ìwọ Ninefe, ni ẹnìkan ti jáde wá Olúwa 12Báyìí ni Olúwa wí: 13Nísinsin yìí ni èmi yóò já àjàgà wọn kúrò ní ọrùn rẹ 14Olúwa ti fi àṣẹ kan lélẹ̀ nítorí tìrẹ Ninefe: 15Wò ó, lórí àwọn òkè,