YOR 1 Cronache Capitolo 2

1 Cronache 2

YOR · Confronta · Audio

1Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Israẹli. Reubeni, Simeoni, Lefi, Juda, Isakari, Sebuluni, 2Dani, Josẹfu, Benjamini; Naftali, Gadi: àti Aṣeri. 3Àwọn ọmọ Juda: Olúwa, bẹ́ẹ̀ ni Olúwa sì pa á. 4Tamari, aya ọmọbìnrin Juda, ó sì bí Peresi àti Sera sì ní ọmọ márùn-ún ní àpapọ̀. 5Àwọn ọmọ Peresi: 6Àwọn ọmọ Sera: 7Àwọn ọmọ Karmi: 8Àwọn ọmọ Etani: 9Àwọn ọmọ tí a bí fún Hesroni ni: 10Ramu sì ni baba Amminadabu, 11Nahiṣoni sì ni baba Salmoni, 12Boasi baba Obedi 13Jese sì ni baba 14ẹlẹ́ẹ̀kẹrin Netaneli, 15ẹlẹ́ẹ̀kẹfà Osemu 16Àwọn arábìnrin wọn ni Seruiah àti Abigaili. 17Abigaili ni ìyá Amasa, ẹni tí baba rẹ̀ sì jẹ́ Jeteri ará Iṣmaeli. 18Kalebu ọmọ Hesroni ní ọmọ láti ọ̀dọ̀ ìyàwó rẹ̀ Asuba (láti ọ̀dọ̀ Jerioti). Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ rẹ̀: 19Nígbà tí Asuba sì kú, Kalebu sì fẹ́ Efrata ní aya, ẹni tí ó bí Huri fún un. 20Huri ni baba Uri, Uri sì jẹ́ baba Besaleli. 21Nígbà tí ó yá, Hesroni sì dùbúlẹ̀ pẹ̀lú ọmọbìnrin Makiri baba Gileadi (ó sì ti fẹ́ ní aya láti ìgbà tí ó ti wà ní ẹni ọgọ́ta ọdún) ó sì bí Segubu. 22Segubu sì jẹ́ baba Jairi, ẹni tí ó jẹ́ olùdarí ìlú mẹ́tàlélógún ní ilẹ̀ Gileadi. 23(Ṣùgbọ́n Geṣuri àti Aramu sì fi agbára gba Hafoti-Jairi, àti Kenati pẹ̀lú gbogbo agbègbè rẹ̀ tí wọn tẹ̀dó sí jẹ́ ọgọ́ta ìlú.) 24Lẹ́yìn tí Hesroni sì kú ni Kalebu Efrata, Abijah ìyàwó rẹ̀ ti Hesroni sì bí Aṣihuri baba Tekoa fún un. 25Ọmọ Jerahmeeli àkọ́bí Hesroni: 26Jerahmeeli ní ìyàwó mìíràn, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Atara; ó sì jẹ́ ìyá fún Onamu. 27Àwọn ọmọ Ramu àkọ́bí Jerahmeeli: 28Àwọn ọmọ Onamu: 29Orúkọ ìyàwó Abiṣuri ni Abihaili ẹni tí ó bí Ahbani àti Molidi. 30Àwọn ọmọ Nadabu 31Àwọn ọmọ Appaimu: 32Àwọn ọmọ Jada, arákùnrin Ṣammai: 33Àwọn ọmọ Jonatani: 34Ṣeṣani kò sì ní ọmọkùnrin àwọn ọmọbìnrin nìkan ni ó ní. 35Ṣeṣani sì fi ọmọ obìnrin rẹ̀ ní aya fún ìránṣẹ́ rẹ̀ Jariha, ó sì bí ọmọ fún tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Attai. 36Attai sì jẹ́ baba fún Natani, 37Sabadi ni baba Eflali, 38Obedi sì ni baba Jehu, 39Asariah sì ni baba Helesi, 40Eleasa ni baba Sismai, 41Ṣallumu sì ni baba Jekamiah, 42Àwọn ọmọ Kalebu arákùnrin Jerahmeeli: 43Àwọn ọmọ Hebroni: 44Ṣema ni baba Rahamu, 45Àwọn ọmọ Ṣammai ni Maoni, 46Efani obìnrin Kalebu sì ni ìyá 47Àwọn ọmọ Jahdai: 48Maaka obìnrin Kalebu sì ni ìyá 49Ó sì bí Ṣaafu baba Madmana, 50Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Kalebu. 51Salma baba Bẹtilẹhẹmu àti Harefu baba Beti-Gaderi. 52Àwọn ọmọ Ṣobali baba Kiriati-Jearimu ni: 53Àti ìdílé Kiriati-Jearimu: àti àwọn ara Itri, àti àwọn ará Puti, àti àwọn ará Ṣumati àti àwọn ará Miṣraiti: láti ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn ọmọ ará Sorati àti àwọn ará Eṣtaoli ti wá. 54Àwọn ọmọ Salma: 55àti àwọn ìdílé àwọn akọ̀wé, ẹni tí ń gbé ní Jabesi: àti àwọn ọmọ Tirati àti àwọn ará Ṣimeati àti àwọn ará Sukati. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ará Keni, ẹni tí ó wá láti ọ̀dọ̀ Hamati, baba ilé Rekabu.

Limite Giornaliero Raggiunto

Aggiorna il tuo piano per continuare a utilizzare le funzioni AI con limiti giornalieri più elevati.

Confronta tutti i piani →