YOR Hosea Pasal 12

Hosea 12

YOR · Bandingkan · Audio

1Efraimu ń jẹ afẹ́fẹ́; 2Olúwa ní ẹjọ́ kan tí yóò bá Juda rò, 3Láti inú oyún ni ó ti di arákùnrin rẹ̀ mú ni gìgísẹ̀, 4Ó bá angẹli ja ìjàkadì, ó sì borí rẹ̀, Olúwa ní Beteli, 5àní Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun; Olúwa ni orúkọ ìrántí rẹ̀. 6Ṣùgbọ́n ìwọ gbọdọ̀ padà sọ́dọ̀ Ọlọ́run rẹ̀; 7Oníṣòwò ń lo òsùwọ̀n èké 8Efraimu gbéraga, 9“Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ; 10Mo sọ fún àwọn wòlíì, 11Gileadi ha burú bí? 12Jakọbu sálọ si orílẹ̀-èdè Aramu; 13Olúwa lo wòlíì kan láti mú Israẹli jáde wá láti Ejibiti, 14Ṣùgbọ́n Efraimu ti mú un bínú gidigidi;

Batas Harian Tercapai

Tingkatkan paket Anda untuk terus menggunakan fitur AI dengan batas harian yang lebih tinggi.

Bandingkan semua paket →