YOR Jeremiás Fejezet 50

Jeremiás 50

YOR · Összevetés · Hang

1Èyí ni ọ̀rọ̀ tí Olúwa fi sẹ́nu wòlíì Jeremiah láti sọ fún ará ilẹ̀ Babeli: 2“Ẹ sọ ọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ sì kéde, 3Àwọn ìlú ní apá àríwá yóò 4“Ní ọjọ́ wọ̀nyí àti ní àkókò náà,” Olúwa wí, Olúwa Ọlọ́run wọn. 5Wọn ó máa béèrè ọ̀nà Sioni, Olúwa 6“Àwọn ènìyàn mi ti jẹ́ àgùntàn tí ó sọnù, 7Gbogbo àwọn tí ó rí wọn, ti pa wọ́n jẹ Olúwa ibùgbé 8“Jáde kúrò ní Babeli, 9Nítorí pé èmi yóò ru, 10A ó dààmú Babeli, Olúwa wí. 11“Nítorí pé inú yín dùn nítorí pé ẹ̀yìn yọ̀, 12Ojú yóò ti ìyá rẹ, ẹni tí ó bí ọ 13Nítorí ìbínú Olúwa, kì yóò ní olùgbé; 14“Dúró sí ààyè rẹ ìwọ Babeli Olúwa. 15Kígbe mọ́ ọn ní gbogbo ọ̀nà! Olúwa, 16Ké afúnrúgbìn kúrò ní Babeli, 17“Israẹli jẹ́ àgùntàn tí ó ṣìnà kiri, 18Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Alágbára, Ọlọ́run Israẹli wí, 19Ṣùgbọ́n, èmi yóò mú Israẹli 20Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì,” Olúwa wí, 21“Kọlu ilẹ̀ Merataimu àti àwọn Olúwa wí, 22Ariwo ogun wà ní ilẹ̀ náà 23Báwo ni ó ṣe fọ́, tí ó sì pín yẹ́lẹyẹ̀lẹ tó, 24Mo dẹ pàkúté sílẹ̀ Olúwa. 25Olúwa ti kó àwọn ohun èlò ìjà rẹ̀ jáde, Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun 26Ẹ wá sórí rẹ̀ láti òpin gbogbo, 27Pa gbogbo àwọn akọ màlúù rẹ, 28Gbọ́ ohùn àwọn tí ó sálọ, tí ó sì sálà láti Babeli wá, Olúwa Ọlọ́run wa ti gbẹ̀san, 29“Pe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, àní gbogbo tafàtafà, sórí Babeli, Olúwa, sí Ẹni Mímọ́ Israẹli. 30Nítorí náà, àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ Olúwa wí. 31“Wò ó, èmi yóò dojú kọ ọ́ ìwọ agbéraga,” Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, 32Onígbèéraga yóò kọsẹ̀, yóò sì ṣubú, 33Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ: 34Síbẹ̀, Olùràpadà wọn, Alágbára, Olúwa Ọlọ́run Alágbára ni orúkọ rẹ̀. 35“Idà lórí àwọn Babeli!” Olúwa wí, 36Idà lórí àwọn wòlíì èké 37Idà lórí àwọn kẹ̀kẹ́-ẹṣin rẹ̀ 38Ilẹ̀ gbígbẹ lórí omi rẹ̀; yóò sì gbẹ. 39“Nítorí náà àwọn ẹranko ijù 40Gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti gba ìjọba Sodomu àti Gomorra Olúwa wí, 41“Wò ó! Ọ̀wọ́ ọmọ-ogun láti ìhà àríwá; 42Wọ́n sì di ìhámọ́ra ọ̀kọ̀ àti ọrun, 43Ọba Babeli ti gbọ́ ìròyìn nípa wọn, 44Bí i kìnnìún ni òun ó gòkè wá láti igbó Jordani 45Nítorí náà, gbọ́ ohun tí Olúwa sọ nípa Babeli, 46Ní ohùn igbe ńlá pé;

Napi korlát elérve

Frissítsd az előfizetésed, hogy az AI funkciókat magasabb napi korlátokkal használhasd.

Összes csomag összehasonlítása →