YOR Prédikátor Fejezet 1

Prédikátor 1

YOR · Összevetés · Hang

1̀rọ̀ Oniwaasu, ọmọ Dafidi, ọba Jerusalẹmu: 2“Asán inú asán!” 3Kí ni ènìyàn rí jẹ ní èrè lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀, 4Bí ìran kan ti wá ni ìran mìíràn ń kọjá lọ, 5Oòrùn ń ràn, oòrùn sì ń wọ̀, 6Afẹ́fẹ́ ń fẹ́ lọ sí ìhà gúúsù, 7Gbogbo odò ń sàn sí inú Òkun, 8Ohun gbogbo ni ó ń mú àárẹ̀ wá, 9Ohun tí ó ti wà tẹ́lẹ̀ náà ni yóò sì máa wà, ohun tí a ti ṣe sẹ́yìn 10Ǹjẹ́ ohun kan wà tí ẹnìkan le è sọ wí pé, 11Kò sí ìrántí ohun ìṣáájú 12Èmi, Oniwaasu ti jẹ ọba lórí Israẹli ní Jerusalẹmu rí. 13Mo fi àsìkò mi sílẹ̀ láti kọ́ àti láti ṣe àwárí pẹ̀lú ọgbọ́n, gbogbo ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run. Háà! Ẹrù wúwo tí Ọlọ́run ti gbé lé àwọn ènìyàn. 14Èmi ti rí ohun gbogbo tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ oòrùn, gbogbo rẹ̀ kò ní ìtumọ̀ bí ẹní gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́ ni. 15Ohun tí ó ti wọ́ kò le è ṣe é tọ́ mọ́, 16Mo rò nínú ara mi, “Wò ó, mo ti dàgbà, ọgbọ́n mi sì ti pọ̀ ju ti ẹnikẹ́ni tí ó ti ṣe alákòóso Jerusalẹmu síwájú mi lọ, mo ti ní ìrírí púpọ̀ nípa ọgbọ́n àti ìmọ̀.” 17Nígbà náà ni mo fi ara jì láti ní ìmọ̀ nípa ọgbọ́n, àti pàápàá àìgbọ́n àti òmùgọ̀, ṣùgbọ́n mo rí, wí pé èyí pẹ̀lú bí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́ ni. 18Nítorí pé ọgbọ́n púpọ̀ ìbànújẹ́ púpọ̀ ní ń mú wá,

Napi korlát elérve

Frissítsd az előfizetésed, hogy az AI funkciókat magasabb napi korlátokkal használhasd.

Összes csomag összehasonlítása →