YOR Jeremija Poglavlje 15

Jeremija 15

YOR · Usporedi · Zvuk

1Nígbà náà ni Olúwa sọ fún mi pé: “Kódà kí Mose àti Samuẹli dúró níwájú mi, ọkàn mi kì yóò lọ sọ́dọ̀ àwọn ènìyàn wọ̀nyí. Mú wọn kúrò níwájú mi! Jẹ́ kí wọn ó lọ! 2Tí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Níbo ni kí a lọ?’ Sọ fún wọn pé, ‘Báyìí ni Olúwa wí: 3“Èmi yóò rán oríṣìí ìjìyà mẹ́rin láti kọlù wọ́n,” ni Olúwa wí, “Idà láti pa, àwọn ajá láti wọ́ wọn lọ, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ẹranko orí ilẹ̀ láti jẹ àti láti parun. 4N ó sọ wọ́n di ẹni ìkórìíra níwájú gbogbo ìjọba ayé torí ohun tí Manase ọmọ Hesekiah ọba Juda ṣe ní Jerusalẹmu. 5“Ta ni yóò ṣàánú rẹ, ìwọ Jerusalẹmu? 6O ti kọ̀ mí sílẹ̀,” ni Olúwa wí, 7Èmi kò tún lè fi ìfẹ́ hàn si ọ, 8Èmi yóò jẹ́ kí àwọn opó wọn pọ̀ ju 9Ìyá ọlọ́mọ méje yóò dákú, Olúwa wí. 10Háà! Ó ṣe tí ìyá mi bí mi, 11Olúwa sọ pé, 12“Ǹjẹ́ ẹnìkan lè fi ọwọ́ ṣẹ́ irin 13“Gbogbo ọlá àti ìṣúra rẹ 14Èmi yóò fi ọ́ ṣẹrú fún àwọn ọ̀tá rẹ 15Ó yé ọ, ìwọ Olúwa; 16Nígbà tí ọ̀rọ̀ rẹ dé, mo jẹ wọ́n, Olúwa Ọlọ́run Alágbára. 17Èmi kò fìgbà kan jókòó láàrín àwọn ẹlẹ́gàn, 18Èéṣe tí ìrora mi kò lópin, 19Nítorí náà báyìí ni Olúwa wí, 20Èmi fi ọ́ ṣe odi idẹ tí ó lágbára, Olúwa wí. 21“Èmi yóò gbà ọ́ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ìkà ènìyàn,

Dnevna Ograničenja Dosegnuta

Nadogradi svoj plan kako bi nastavio/nastavila koristiti AI značajke s većim dnevnim ograničenjima.

Usporedi sve planove →