YOR सपन्याह अध्याय 3

सपन्याह 3

1Ègbé ni fún ìlú aninilára, 2Òun kò gbọ́rọ̀ sí ẹnikẹ́ni, Olúwa, 3Àwọn olórí rẹ̀ jẹ́ kìnnìún tí ń ké ramúramù, 4Àwọn wòlíì rẹ̀ gbéraga, 5Olúwa ni àárín rẹ̀ jẹ́ olódodo; 6“Èmi ti ké àwọn orílẹ̀-èdè kúrò, 7Èmi wí fún ìlú náà wí pé, 8Nítorí náà ẹ dúró dè mí,” ni Olúwa wí, 9“Nígbà náà ni èmi yóò yí èdè àwọn ènìyàn padà sí èdè mímọ́, Olúwa, 10Láti òkè odò Etiopia, 11Ní ọjọ́ náà ni a kì yóò sì dójútì 12Ṣùgbọ́n Èmi yóò fi àwọn ọlọ́kàn tútù Olúwa. 13Àwọn ìyókù Israẹli kì yóò hùwà ibi, 14Kọrin, ìwọ ọmọbìnrin Sioni, 15Olúwa ti mú ìdájọ́ rẹ wọ̀n-ọn-nì kúrò, Olúwa, ọba Israẹli wà pẹ̀lú rẹ; 16Ní ọjọ́ náà, wọn yóò sọ fún Jerusalẹmu pé, 17Olúwa Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ, 18“Èmi ó kó àwọn tí ó ń banújẹ́ fún àjọ̀dún tí a yàn jọ, 19Ní àkókò náà 20Ní àkókò náà ni èmi yóò ṣà yín jọ; Olúwa wí.

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →