YOR नीतिवचन अध्याय 9

नीतिवचन 9

1gbọ́n ti kọ́ ilé rẹ̀, 2ó ti fi ilé pọn tí, ó ti fọ̀nà rokà. 3ó ti rán àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ jáde, ó sì ń pè, 4“Jẹ́ kí gbogbo àwọn aláìgbọ́n wọ ibí wá!” 5“Wá, ẹ wá jẹ́ oúnjẹ mi 6Fi ìwà àìmọ̀kan rẹ sílẹ̀ ìwọ yóò sì yè; 7“Ẹnikẹ́ni tí ó bá bá ẹlẹ́gàn wí, kọ lẹ́tà sí àbùkù 8Má ṣe bá ẹlẹ́gàn wí, àìṣe bẹ́ẹ̀ yóò kórìíra rẹ. 9kọ́ ọlọ́gbọ́n ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́, yóò sì gbọ́n sí i 10“Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n, 11Nítorí nípasẹ̀ mi ọjọ́ rẹ yóò gùn 12Bí ìwọ bá gbọ́n, ọgbọ́n rẹ yóò fún ọ ní èrè: 13Òmùgọ̀ obìnrin jẹ́ aláriwo; 14Ó jókòó ní ẹnu-ọ̀nà ilé rẹ̀ 15ó ń pe àwọn tí ó ń kọjá lọ, 16“Jẹ́ kí gbogbo ẹni tí ó jẹ́ aláìlóye súnmọ́ bí!” 17“Omi tí a jí mu dùn 18Ṣùgbọ́n wọn ò funra pé àwọn òkú wà níbẹ̀,

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →