YOR यिर्मयाह अध्याय 6

यिर्मयाह 6

1Ẹ̀yin ènìyàn Benjamini, sá sí ibi ààbò! 2Èmi yóò pa ọmọbìnrin Sioni run, 3Olùṣọ́-àgùntàn pẹ̀lú agbo wọn yóò gbóguntì wọ́n. 4“Ẹ ya ará yín sí mímọ́ láti bá a jagun! 5Nítorí náà, ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a kọlù ú ní àṣálẹ́ 6Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Àwọn ọmọ-ogun wí: 7Gẹ́gẹ́ bí kànga ṣe ń da omi inú rẹ̀ sílẹ̀, 8Ìwọ Jerusalẹmu, gba ìkìlọ̀, 9Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: 10Ta ni ẹni tí mo lè bá sọ̀rọ̀ àti tí mo lè fún ní ìmọ̀ràn? Olúwa, jẹ́ ohun búburú sí wọn, 11Èmi kún fún ìbínú Olúwa, 12Ilé wọn o sì di ti ẹlòmíràn, Olúwa wí. 13“Láti orí ẹni tí ó kéré sí orí ẹni tí ó tóbi ju, 14Wọ́n sì ń wo ọgbẹ́ àwọn ènìyàn 15Ojú ha a tì wọ́n nítorí ìwà ìríra wọn bí? Olúwa wí. 16Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 17Èmi yan olùṣọ́ fún un yín, 18Nítorí náà, gbọ́ ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; 19Gbọ́, ìwọ ayé! 20Èrè wo ni ó wà fún mi nínú tùràrí láti Ṣeba wá, 21Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí: 22Báyìí ni Olúwa wí: 23Wọ́n sì dìmọ́ra pẹ̀lú ọrun àti ọ̀kọ̀, 24Àwa ti gbọ́ ìròyìn nípa wọn, 25Má ṣe jáde lọ sí orí pápá 26Ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ gbé aṣọ ọ̀fọ̀ wọ̀, 27“Èmi ti fi ẹ́ ṣe ẹni tí yóò máa yọ́ 28Ọlọ́tẹ̀ tí ọkàn rẹ̀ le ní gbogbo wọn. 29Ewìrì a fẹ́ná kíkankíkan, 30A pè wọ́n ní fàdákà tí a kọ̀sílẹ̀, Olúwa ti kọ̀ wọ́n sílẹ̀.”

दैनिक सीमा तक पहुंच गई

उच्च दैनिक सीमा के साथ AI सुविधाओं का उपयोग जारी रखने के लिए अपनी योजना को अपग्रेड करें।

सभी योजनाओं की तुलना करें →